Home / Àṣà Oòduà (page 20)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Ìjọba àpapọ̀ f’ẹ́ já iná mànàmáná orílẹ̀èdè Togo àti Benin Republic nítorí gbèsè $7m

Ìjọba àpapọ̀ f’ẹ́ já iná mànàmáná orílẹ̀èdè Togo àti Benin Republic nítorí gbèsè $7m Ariwo t’íjọba àpapọ̀ Nàìjíríà ń pa lé àwọn tó jẹ ẹ́ ni gbèsè owó iná nìyí báyìí o. Ṣùgbọ́n lọ́tẹ̀ yìí kìí ṣe àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè ...

Read More »

Ó di láyéláyé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè

Ó di láéláé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè Gbajúgbajà òṣèré Samuel Akinpẹlu tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àlàbí Yellow ti jẹ́ Ẹlẹ́dàá nípè. Akọni tí à ń perí yìí jẹ́ òṣèré tí àwọn èèyàn kò ...

Read More »

Àlùfá tọ́ bá ọmọ ọdún méje sùn, wẹ̀wọ̀n ọdún Márùn- ún ní ìpínlẹ̀ Ekiti

Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n t’olóhun.Ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti tífìtàn balẹ̀ bí wọ́n ṣe jẹ́ ìpínlẹ̀ àkọ́kọ́ tí yóò bẹ̀rẹ̀ láti máa dárúkọ ọ̀daràn afipá bánilòpọ̀ hàn àti láti máa dójú tì wọ́n. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Kayode Fayemi gbé ...

Read More »

Ìdí tí a fi yọ Donald Trump nípò Ààrẹ

Alágbára ayé,alágbára ayé,a sè a ṣẹ̀ má lù kan, Ọlọ́run o tíì da sí dúníyàn .Bí nǹkan se n lọ yìí, Donald Trump ni Ààrẹ orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà kẹta nínú ìtàn tí ọ̀bẹ yóó bá ń dìí láti ọ̀dọ̀ àwọn Ilé ...

Read More »

Kò sí ilé tàbí só̩ò̩bù tí a kò le fo̩ láti ké̩rù òfin – Àjo̩ Customs

Awon ajo asobode ile Nigeria ti gbogbo eniyan mo si Customs ni won n ba awon oniroyin soro ni ipinle Adamawa pe, ko si ile tabi soobu ti awon ko le ja tabi fo ti o ba ye.Won ni gbogbo ...

Read More »

Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’Ekiti

Àsíá pupa dá ìjayà sílè̩ l’EkitiYinka AlabiIdaji oni ojo kokanlelogun, osu kejila odun yii ni awon ara ilu Orin Ekiti dede de oko ti won ba Asia pupa to tumo si wi pe, ki awon ara agbegbe naa ma se ...

Read More »

Ilé Ẹjọ́ Tó Ga Jù Dá Seyi Makinde Láre Gẹ́gẹ́ Bíi Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Ilé ẹjọ́ tó ga jù dá Seyi Makinde láre gẹ́gẹ́ bíi gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀rọ̀ Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lọ́wọ́-lọ́wọ́ onímọ ẹ̀rọ Ṣèyí Mákindé tí di ọmọ oṣupa lé ẹ̀ ní kò gún,……bí Ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ lórílẹ̀-èdè ...

Read More »

Kini a npe eleyi ni ede kaaro o ojire?

Read More »

Ìdí tí Oluwo fi kọ Olorì rẹ̀ sílẹ̀ rèé

Ìdí tí Oluwo fi kọ Olorì rẹ̀ sílẹ̀ rèé Fẹ́mi Akínṣọlá Kábíèsí Oluwo ti ìlú Ìwó, Ọba Abdulrosheed Adewale ti kọ Olorì rẹ̀ Chanel Chin sílẹ̀. Agbẹnusọ fún Kábíèsí ọ̀hún, Alli Ibrahim fi ìdí ọ̀rọ̀ náà mulẹ fún akọ̀ròyìn. Bí ...

Read More »

Àhes̩o̩ ò̩rò̩ ni ikú Babangida

Aheso oro ni iku BabangidaYinka AlabiAriwo iku ajagunfehinti to o tun je Aare Ologun ni orileede yii tele ri, Ibrahim Babangida ni o gbode Kan.Ariwo yii po lori ero ayelujara lati idaji oni sugbon Ogbeni Kazim Afegbua ni iro ni. ...

Read More »