Home / Àṣà Oòduà (page 30)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Tàgiiri

Tàgiiri ma yí nìsó Ara rẹ lokùn Ara rẹ ní ajé gbe ńso

Read More »

Ẹ̀yẹ̀lé

Yiyẹ̀ lonyẹ́ ẹ̀yẹ̀lé, Ayé ayẹ̀ wá kàlẹ̀, Rirọ lonrọ àdábà lọrún, Ayé yio rọrún fún wá jẹ̀,

Read More »

Ifá naa ki bayi wipe: Osa Alawure (Osa Otura) – Otua Meji

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, adura wa yio gba, ori buruku koni je tiwa loni o Àse. Mo nfi akoko yi nki gbogbo onisese patapata kaakiri agbaye wipe aku aseyori odun ifá agbaye o , a ku odun a sin ku iyedun o, emin wa yio se pupo re ninu ola ati idera lase Eledumare.

Read More »

Ẹ Káàbọ̀ sí oṣù tuntun

Oṣù Òkúdù á yanjú gbogbo ohun tí ó ń dùn wá lọ́kàn Ẹnikẹ́ni ò sì ní bá wa du’re ayọ̀ wa. @AlamojaYoruba

Read More »

Bí ewúrẹ́ bá bojú wo ẹ̀yìn

Á fi èpè fún elépè Mo sé ní ìwúre wípé gbogbo ọ̀tá tí o bá ń robi tàbí sebi sí èmi àti ẹ̀yin lẹ́yìn yoo ma fí orí ara wọn gbe láṣẹ Ọlọ́run Olódùmarè Àsẹ Eu oro para que qualquer inimigo ...

Read More »

Ọmọ: Ẹ̀bùn Edùmarè !

Ẹ̀bùn Edùmarè ni ọmọ Ẹ̀rí ìfẹ́ rẹ̀ sí wa ni wọ́n Èdùmàrè à ń bẹ̀ ọ́ Bá wa wo àwọn èwe yè Fi wọ́n fún àwọn tí ń wojú rẹ fún ẹ̀bùn wọn Má ṣe jẹ́ kí wọ́n kú mọ́ ...

Read More »

Pari Owe Yii

Ohun to wa leyin Ofa!

Read More »

Asiri àwo kintú,

Asiri ẹ̀tú kintú, Iwọ iwori bógbè IFA, Ki owá bo asiri mi, Iwọ iwori bógbè. Mogbá ládùrá wipè loni ọjọ àbámẹtá asiri gbógbó wa koni tu kotobó lailai,gbogbo abá ti aba da loni yio jẹ mimusẹ, Aṣẹ̀ aṣẹ̀ aṣẹ̀. Aṣẹ̀ aṣẹ̀ aṣẹ̀.

Read More »

Àwon tí ó n gbélè sunkún síta fún ìrànlówó nígbà tí àwon adigunjalè jàwón lólè ní Bayelsa.

Àwon olùgbé Opolo ní Yenagoa ìpínlè Bayelsa ni ìbèrùbojo ti gba okàn won léyìn tí àwon adigunjalè jà won lólè tán. Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè yí kojá ogbòn tí won sì gbé àwon ohun ìjà olóró lówó ...

Read More »

Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún.

Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún. Arábìnrin kan tí a kò fi taratara mo orúko rè súgbón tí kò le jú omo odún méèdógún sí ogbòn kan ni ó so ...

Read More »