Home / Iroyin Pajawiri (page 6)

Iroyin Pajawiri

È̩yin òsìsé̩ mi nílò àyè̩wò coronavirus kíákíá- Akeredolu

È̩yin òsìsé̩ mi nílò àyè̩wò coronavirus kíákíá – Akeredolu Arakunrin Rotimi Akeredolu ti o je gomina ipinle Ondo lo n gba awon alabasise re niyanju ki won fi oro ti oun se arikogbon. O ni iba lasan ni o se ...

Read More »

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC Ijoba apapo ti fowo si aba ti awon ajo NCDC gbe lo si odo Aare. Ijoba fi aaye sile ki awon ara ilu maa rin ...

Read More »

Keyamu àti àwo̩n Asojú sòfin tutó̩ sí ara wo̩n lójú

Keyamu àti àwo̩n Asojú sòfin tutó̩ sí ara wo̩n lójú Minisita fun ipinle ati eto ise ni orileede yii, Agbejoro agba Festus Keyamu ni awon Asoju sofin ranse si ni ilu Abuja lonii. Won fi saarin, won si bere si ...

Read More »

Mí ò ì pinnu lóri ìdíje Ààrẹ ọdún 2023-Tinubu

Mí ò ì pinnu lóri ìdíje Ààrẹ ọdún 2023-Tinubu Báá ti ṣe làá wí, ẹnìkan kìí yan àna rẹ̀ lódì ni Yorùbá wí àsamọ̀ yìí ló díá fún bí asáájú ẹgbẹ́ òṣelú ẹgbẹ́ APC, Sẹ́nétọ̀ Bola Ahmed Tinubu tí ṣọ ...

Read More »

Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn

Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn Ọlọ́jọ́ ń kajọ́, ẹ̀dá ò fiyè si.Ìjọ ọmọ tuntun dáyé, nijọ́ ìdùnnú, ẹ̀rín, òhun ọ̀yàyà fún ẹbí,ará, pẹ̀lú ìyekan. Ṣùgbọ́n kìí rọgbọ ká sàdédé sàfẹ̀kù èèyàn ẹni pékú yọwọ́ ọ rẹ̀ ní dúníyàn. Àsamọ̀ ...

Read More »

Abiola Ajimobi sùn un re

Ikú pàgbẹ̀ àṣírí aláró tú.Ikú pàlùkò àbùkù kará ìkosùn.Ọrùn má kánjú, gbogbo wa la dágbádá ikú.Ìgbà átàsìkò ẹ̀dá ló só kùnkùn.Gíńgín ladáhunṣe tó mewé e re.Gbogbo wa lòpè nípa àkúnlẹ̀yàn.Òkú ń sunkú òkú, akáṣọlérí ń sunkú ara a wọn.Sùn un ...

Read More »

INEC kọ lẹ́tà APC láti ṣe ìbò abẹ́nú l‘Ondo

INEC kọ lẹ́tà APC láti ṣe ìbò abẹ́nú l‘Ondo Ṣé àwọn àgbà ní bí eégún kò bá ṣe n tó tóbi, atọ́kùn rẹ̀ kìí tú ìdí rẹ̀ wò. Àjọ olómìnira tó ń ṣe kòkárí ètò ìdíbò Orílẹ̀ yìí tí fọnmú ...

Read More »

Igbákejì gómìnà Òǹdó Agboola Ajayi tilé APC bọ́sí yẹ̀wù PDP

Igbákejì gómìnà Òǹdó Agboola Ajayi tilé APC bọ́sí yẹ̀wù PDP Ó dà bíi pé , ẹ kú àtilé bọ́ọ́lé ló kù báyìí, tí àwa òlùdìbò yóó ma kí àwọn olóṣèlú wọ̀nyí lásìkò yìí, tí wọ́n kàn ń múwa ṣeré nínú ...

Read More »

Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin?

Aku ataro óò Adé kú ọjọ yìí Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin náà?????? #iya lájé

Read More »

Eṣọ́ àjọ FRSC mẹ́ta tí ààrá sán pa gbọdọ̀ ṣ’ètùtù – Ẹlẹ́buùbọn

Eṣọ́ àjọ FRSC mẹ́ta tí ààrá sán pa gbọdọ̀ ṣ’ètùtù – Ẹlẹ́buùbọn Ṣé ọlọ́tọ̀ ní t’óun ọ̀tọ̀, a díá fún òkú tó kú ńlé, tí wọ́n sin s’óko.Àgbà Imọlẹ̀ kan nlẹ yìí ti fèsì sí ìṣẹ̀lẹ̀ ààrá tó sán láìpẹ́ ...

Read More »