Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 11)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Miracle Ikechukwu dé ìlú Imo léyìn ìsinmi olójó gbooro, tí ó pín àwòrán

Miracle Ikechukwu dé ìlú Imo léyìn ìsinmi olójó gbooro, tí ó pín àwòrán . Gbajúgbajà Bbnaija tí a mò sí Miracle tí ó lo fún ìsinmi olójó gbooro ti padà sí orílè èdè Nìjíríà gégé bí ó se kakè sí ...

Read More »

Reekado Banks gba Larry Ekundayo l’álejò ní ilé rè.

Omo ikò ti egbé olórin ìgbàlódé tí a mò sí Mavin, Reekado Banks ti gba okùnrin a gba àmì èye ní àlejò ní ilé rè, àwon méjèjì pín fídíò náà sí orí èro ayélujára. E wo àwòrán won ní ìsàlè.

Read More »

Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu.

Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu. Arákùnrin kan ni a rí ní Ayobo, agbègbè kan ní ìpínlè Èkó tí ó n fi ìtò ara rè wè tí ó rò wípé omi ni látàrí ìmukúmu ...

Read More »

Ayé Kareem ti yí padà di òtun láti ìgbà tí ó ti ya àwòrán Ààre Macron- Alákoso rè ló so béè.

Óríre míràn ti to omo kékeré, omo odún mókànlá tí a mò sí Kareem Waris Olamilekan tí olórun fún ní èbùn kí ó ma ta nkan, ó ti ya ààre ilè Faransé tí a mò sí Ààre Emmanuel Macron, nígbà ...

Read More »

Ìròyìn Òrofó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

1 Ààrẹ Buhari yóò dé lónìí láti orílẹ̀ èdè China. 2 Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀ṣínbàjò gba àlejò àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọn gbé igbá orókè nínú ìdíje ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé. 3 Àwọn oníròyìn ń fi ìròyìn burúkú bá ìjọba Buhari ...

Read More »

Arábìnrin kan ni ó bí ìbeta léyìn odún métàdínlógún tí ó tí se ìgbéyàwó.

Arábìnrin kan ni ó gbe lo sí orí èro ayélujára tí a mo sí facebook láti lo pín ìròyìn ayò wípé òhun bí ìbeta láti bí odún métàdínlógún sèyìn. Ó ko síbè wípé… ” èyin abiyamo mi ò le mú ...

Read More »

Àwon omo egbé APC ti Gúúsù Oyo ti jóòkó ìgbìmò – Abiola Ajimobi lo kí Alaafin Oyo.

Gómìnà ìpínlè Oyo , Abiola Ajimobi , tí ó ti fi okàn àwon omo egbé APC ti ìpínlè Oyo lókàn balè wípé omo egbé àwon ló ma wolé ní ibi ìdìbò tí ó n bò lónà ní odún 2019, àti ...

Read More »

Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.

Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún. Olùsó Daniel Udoh, tí ó dá ilé ìjosìn “Agbejórò ni jésù” sílè ni owó sìkún ìjoba ti tè ní Akapabuyo, ìpínlè Cross river látàrí ...

Read More »

Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.

Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC. Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Ogbeni Rauf Aregbesola ti gun orí ténté okò láti polongo egbé won, egbé oní ìgbálè tí a mò sí ...

Read More »

Akékòó bìnrin méjì ja ìjàgbara látàrí òrékùnrin ní ilé-èkó gíga ifáfitì tí a mò sí Tai solarin University of Education, ní ìpínlè Ogun.

Fídíò àti àwòrán àwon òdóbìnrin méjì tí ó ñ jà látàrí òrékúnrin kan ni ó ti gbalè kan . Akékòó ni àwon arábìnrin méjì yí àti wípé akékòó ilé-èkó ifáfitì ti Tai Solarin University Of Education ni won, ìpínlè Ogun, ...

Read More »