Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 22)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Reekado banks wà pèlú àwon òdóbìnrin tí won yááyì “ka bíbélì re kí o sì gbàdúrà lójojúmò.

Ìkan lára àwon omo olórin abé ikò Marvin, Reekado banks pín àwòrán sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram, èyí tí ó yà pèlú àwon òdóbìnrin tí won férè wà ní ìhòhò. Tí ó sì ko síbè pé ...

Read More »

Oríkì Ìjẹ̀bú

Oríkì Ìjẹ̀bú Ìjẹ̀bú ọmọ alárè, Ọmọ awujálè, Ọmọ arójò joyè, Ọmọ alágemo Ògún, Ọmọ aladìye ògògòmógà, Ọmọ adìye bàlókùn, Ara òrokùn, Ara ò radìye, Ọmọ ohun ṣéní, òyòyò mayòmo ohun ṣéní, olèpani, ọmọ dúdú ilé komobe ṣe níJósí, Ọmọ moreye ...

Read More »

Arákùnrin ológun tí ó rewà ti setán láti fé ààyò okàn rè, e wo àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won.

    “Àkókò ti wá tó báyìí kí arákùnrin yí fi ìyá àti bàbá rè sílè láti gbárùkù ti ìyàwó rè, kí àwon méjèèjì sì di òkan. Láì dóònà p’enu, eni wa, Okeoma Daniel Onyenaturuchi ti setán láti lo ìgbésí ...

Read More »

Arábìnrin kan tí ó jé omo Liberia ni ó gé nkan omokùnrin òrékùnrin rè tí òrékùnrin rè sì pa á.

Arábìnrin kan tí ó jé omo Liberia ni ó gé nkan omokùnrin òrékùnrin rè tí òrékùnrin rè sì pa á. Èyin òré wa, ejòwó e jé kí á máa fura nítorí a kò mo irú àwon obìnrin tí à n ...

Read More »

Davido àti òrébìnrin rè tí a mò sí Chioma Alvrid ní Barbados.

Davido àti òrébìnrin rè, Chioma wà ní Barbados báyìí báyìí láti ya àwòrán Orin tuntun tí Davido sèsè ko. Ó ti pín àwòrán òun àti arábìnrin yí ní orí èro ayélujára tí a mò sí instagram tí ó sì ko ...

Read More »

Arábìnrin tí ó ti ń pa àwon ará ìlú rè ni owó ti bà tí won sì ti fi se èsin Abia.

Gégé bí ìròyìn se so, arábìnrin tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí tí ó wá láti Amuda Isuochi ní ìpínlè Abia, ni ó ti ń pa àwon èèyàn ìlú rè, ò n lò èro ayélujára tí ó pín àwòrán ...

Read More »

Ẹ̀kọ́ àti Ọgbọ́n ni Ọ̀rọ̀ Àgbà lati Ẹnu Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ lórí Ẹ̀rọ Amóhùnmáwòrán Òpómúléró

Bi a ba fi eti si ọ̀rọ̀ ti àgbà Yorùbá Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọmọlolú Olunlọyọ  ni ori ẹ̀rọ “Amóhùnmáwòrán Òpómúléró”, ni ori ayélujára, a o ṣe àkíyèsí àwọn nkan wọnyi: Video Player  Ọ̀jọ̀gbọ́n Olunlọyọ fi àṣà Yorùbá ti ó ti ńparẹ́ hàn ...

Read More »

Arákùnrin àti arábìnrin IPOB gun òkadà léyìn tí won lo se àbèwò Nnamdu kanu.

Arákùnrin àti arábìnrin IPOB gun òkadà léyìn tí won lo se àbèwò Nnamdu kanu. Àwon èèyàn yí kò kúkú ní pa mí, arákùnrin Kan tí a mò sí Nwaiwu Chiukwuebuka ni a rí pèlú arábìnrin Kan lórí òkadà Kan náà.

Read More »

Murphy Afolabi se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún kerin lé l’ógójì ní Toronto, Canada.

Òsèré orí ìtàgé, Murphy Afolabi se ayeye ojó ìbí rè ní ojó mélòó séyìn. Òré àti ojúlùmò tí won jé èníyàn pàtàkí, gbajúgbajà Òsèré, adarí eré abbl ti se ayeye ìjònilójú fún omo bíbí ìpínlè Osun tí a bí ní ...

Read More »

Akékòó odún kerin tí ó rì s’ómi ní Yankari.

Gabriel Emmanuel Chinoso, tí ó jé Akékòó olódún mérin tí se Akékòó eka èkó onímò nípa ohun amáyé rorùn tí a mò sí electrical engineering ní ilé-èkó gíga Tafawa Balewa university, Bauchi ni ati gbó wípé òkú sí inú odò ...

Read More »