Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 60)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Oriki Ibeji

Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, ...

Read More »

Odu Ifa Owonrin Tutu/ Oturupon

| |  | | | |  | |  |     | | |   |   Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio gbo adura wa o yio si bawa tu ile aye to ...

Read More »

“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo….

“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo Wun ó bí’mo lé’mo n tó máalo Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo Bí Wón n n’íre lórun èmi ò mò Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo I will have enough ...

Read More »

Egbo talo daran egbaafa ninu awon mejeji ?

Alabahun (ijapa) lo re ile ana re oni ohun le so epa mefa di egbaafa ki odun to yipo, alabahun gbin epa tan ikun de’be o wu epa je ni ijapa ba ni ikun ti daran egbaafa. Ibeere talo daran ...

Read More »

Ogulutu Oro Toni – 09.08.2016

Hummmmmm onilari koseda tomola ‪#‎woo_orewa‬ Bo ba ndara fun o loni mase fi omolakeji re se yeye Mofe koranti pe kise agbara re ni ipo towa loni ‪#‎gbomi_dada‬ Iyanju lagbe ngba obami oke lo nmusu(yam) ta, bi agbara ba nbe ...

Read More »

Òró gangan la nba Òsùn.

Read More »

A ku Ose Sango!

Owonrin Odi I II II II II I I I Owonrin sindin sapere Adifafun Bata abufun Sango nijo won torun bowaye ebo won ni kiwon ose awon mejeji gbebo won sisebo Bata ni owonrin sindin sapere Sango ani okuu temi ...

Read More »

Ori Eni Lawure Eni O – Iyalorisa Omitonade Ifawemimo

Ori Eni Lawure Eni O Ori Eni Lawure Eni Mo ji lowuro mo dewo mori O Ori Eni Lawure Eni… Ki Ori wa ma sowa nu ooo… Ase Ire O! Translation One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell(2ce) I woke ...

Read More »

Owe ati Ibeere Toni – 05.08.2016

– Dabimoseda Alaisan toni ohun o je eyin(egg) ejo(snake) Ibeere Toni -nje IFE otito siwa bi tati jo mo bi?

Read More »

“B’éni l’ówó bí ò n’íwà, owó olówó ni

B’éni l’áya bí ò n’íwà, aya aláya ni B’éni bí’mo bí ò n’íwà, omo olómo ni If one has money but lack character, it’s someone else money If one has wife but lack character, it’s someone else wife If one ...

Read More »