Home / Tag Archives: Ede Oodua (page 13)

Tag Archives: Ede Oodua

Ẹgbẹ́ Àwọn Àgbààgbà Oòduà Ní Osinbajo Kò Gbọdọ̀ Kọ̀wé Fipò Ẹ̀ Sílẹ̀

Ẹgbẹ́ àwọn àgbààgbà Yorùbá ní Osinbajo kò gbọdọ̀ kọ̀wé fipò ẹ̀ sílẹ̀ Ẹgbẹ́ àwọn àgbààgbà Oòduà (Yorùbá) ní Osinbajo kò gbọdọ̀ kọ̀wé fipò ẹ̀ sílẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Èyí ò tófò, kò tófò,fìlà aráabí kù rébété, Kemi Adeoṣun lọ , orí ...

Read More »

Ìjọ Kátólíkì Bẹ̀rẹ̀ Ìwáàdì Lẹ̀yìn Tí Àwọn Sisitá Méjì Lóyún Ójijì

Ìjọ Kátólíkì bẹ̀rẹ̀ ìwáàdì lẹ̀yìn tí àwọn sisitá méjì lóyún ójijì Ìjọ Kátólíkì bẹ̀rẹ̀ ìwáàdì lẹ̀yìn tí àwọn sisitá méjì lóyún ójijì Fẹ́mi Akínṣọlá Eemọ̀ lukutu pẹ́bẹ́,kò síbi tí ìṣe ò sí. Ayé dojú kejì, wọ́n ń bámí ẹran níhòòdí ...

Read More »

N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele

N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹ̀dá ò láròpin láyé, ṣé bí ó se wu Olúwa Ọba níí sọlá, fẹ́ni Ó wù ú,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ níbi tí t’ọba, tìjòyè, ọ̀tọ̀kùlú ìlú ...

Read More »

Àṣírí Pásìtọ̀ Tó Ń Fí Sọ́ọ̀si Ṣe Ọ̀gbà Wèrè Tú

Àṣírí pásìtọ̀ tó ń fí sọ́ọ̀si ṣe ọ̀gbà wèrè tú Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé biribiri òkuǹkùn ọ̀rọ̀ lójú ọmọ aádámọ̀ ,ìmọ̀lẹ̀ gbòò ni lójú Adẹ́dàá. Ní báyìí, Olùsọ́ àgùtàn Joseph Ojo, ní ọwọ ṣìnkún ọlọpàá ti mú fún lílo ilé ìjọsìn ...

Read More »

Ayédèrú ni ‘plate number Chief Whip’ Kano – FRSC

Iroyin asise nomba moto asofin ilu Kano, Ogbeni Ayuba Durum ran kaakiri bi ina inu oye, paapaa julo lori ero ayelujara. Eyi wa ya gbogbo aye lenu pe se bee ni awon ajo FRSC tii se adari eto irinna ati ...

Read More »

Lai Mohammed fa o̩mo̩ Naijiria létí lórí ìròyìn òfegè

Lai Mohammed fa ọmọ Nàìjíríà létí lórí ìròyìn òfegè Fẹ́mi Akínṣọlá Mínísítà ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Ìròyìn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Lai Mohammed ti ní ìjọba yóò bẹ̀rẹ̀ ṣí í ṣe àmójútó àtagbà ojú òpó ayélujára báyìí.Ìgbésẹ̀ yìí ni láti ṣe àfọ̀mọ́ ojú ...

Read More »

Atiku tún pàdánu nílé e̩jó̩ tó ga jù

Atijo tun padanu nile ejo to ga juLati owoYinka AlabiIle-ejo to ga ju lo ni orileede yii ti se idajo lori ejo ti oludije dupo Aare ni abe egbe oselu PDP, Alhaji Atiku Abubakar.Ile-ejo ni Aare Muhammadu Buhari naa ni ...

Read More »

Èmi kò fé̩ràn láti máa fe̩nu ko obìnrin lé̩nu nínú eré – Taiwo Hassan

Taiwo Hassan Ọlọ́jọ́ọ̀bí, akọni òṣèré Yollywood tó dáńtọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Yoòbá bọ̀, wọ́n ní èèyàn tó bá monú-ún rò, ọpẹ́ ẹ rẹ̀ yóó lékún bóyá n ló fa sábàbí bí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ọmọ Nàìjíríà ti ń darapọ̀ kí àgbà òṣèré Taiwo ...

Read More »

Akpabio fajúro sí owó ìnákúùná Niger Delta

Akpabio fajuro si owo inakuna Niger DeltaLati owoYinka AlabiIjoba apapo ti Senato Akpabio n soju fun lo ti gbanaje lori awon ise ajanbaku to n waye ni agbegbe Niger Delta. Akpabio ni o ye ki ise ijoba maa te siwaju ...

Read More »

Màmá àádó̩rin o̩dún ròó pin sí ófíìsì àwo̩n oníná mò̩nàmó̩ná

Màmá àádó̩rin o̩dún ròó pin sí ófíìsì àwo̩n oníná mò̩nàmó̩náLati owoYinka AlabiIya agbalagba ti ko din ni aadorin odun lo lo roo pin si ofiisi ajo apina-ka (IBEDC) Ibadan Electricity Distribution Company to fi ikale si ilu Osogbo.Mama yii di ...

Read More »