Home / Tag Archives: Ede Oodua (page 9)

Tag Archives: Ede Oodua

Nnkan méje ti yóò yipada àti meje ti kò ni yi pada lẹ́yìn ti ilẹ Gẹ̀ẹ́si ti kuro labẹ EU

Lẹ́yin ọdún mẹ́ta lílọ bibọ̀ lórí ọ̀rọ̀ Brexit, ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́ṣì padà kúrò lábẹ́ EU ní aago mọ́kànlá alẹ́ ọjọ́ Jimọ ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù kínní ọdún 2020.

Read More »

Kí gbogbo àwọn olórí ààbò lọọ rọ́kún nílé – Ilé ìgbìmọ̀ asojú

Kí gbogbo àwọn olórí ààbò lọọ rọ́kún nílé – Ilé ìgbìmọ̀ asojúLáti ọwọ́ Yínká Àlàbí Abajade ipade ile igbimo asoju to wa ni Abuja ni “a kuku joye san ju enu mi ko ka ilu lo”. Won ni ki gbogbo ...

Read More »

Jonathan sàbẹ̀wò sí Buhari

Ara iroyin yajoyajo to wole ni abewo ti Aare ana, Omowe Goodluck Jonathan se si Aare Mohammadu Buhari ni Aso Villa to wa ni oluulu Naijiria ni Abuja. Ipade bonkele ni ipade yii nitori pe awon mejeeji tilekun mori ni, ...

Read More »

Ò̩pò̩ dúkìá sègbé sínú ìjàm̀bá iná ló̩jà Amu l’Ekoo

Ò̩pò̩ dúkìá sègbé sínú ìjàm̀bá iná ló̩jà Amu l’EkooLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíEledua jowo maa so wa pelu ijamba ina to n sele lasiko eerun yii.Lojiji ni ijamba tun be yo ni oja gbaju-gbaja Amu ti o wa ni ilu Mushin ...

Read More »

Ilé-ẹjọ́ Tó Ga Jù Ní Samuel Ortom Náà Ló Tún Jáwé Olúborí Ní Benue

Ilé-ẹjọ́ tó ga jù ní Samuel Ortom náà ló tún jáwé olúborí ní BenueLáti ọwọ Yínká Àlàbí Iroyin yajoyajo to wole bayii lo n jeri sii bi ile ejo to ga ju lo to fi ikale si ilu Abuja se ...

Read More »

Ìjọba Àpapọ̀ Kò Gbẹ́sẹ̀lẹ̀ Lé Owó Tó Tọ́ Sáwọn Ìjọba Ìbílẹ̀ L‘ọyọ

Lórí ọ̀rọ̀ kan tó gbà gboro kan pé àgbẹjọrò àgbà orilẹ̀-èdè Naijiria, Abubakar Malami ti pàṣẹ fún gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo láti gba àwọn alága káńṣù ti wọ́n yọ nípò pada, Ìjọba Ọyọ ti fèsì lórí ìṣẹ̀lẹ̀ náà.

Read More »

Ó ju ẹnu Malami lọ láti ní ètò náà kò bófin mu

Kí ojú má ríbi, gbogbo ara lòògùn rẹ̀, èyí ló mú kí Gómìnà ipinlẹ Ọyọ, Ṣèyí Mákindé sáré tètè gba ìlú Abẹokuta lọ, láti lọ ṣèpàdé pọ̀ pẹ̀lú Olóyè Olusẹgun Ọbasanjọ.

Read More »

Ìdí tí nó̩ḿbà ìdánimò̩ kò fi jé̩ dandan mó̩ – Àjo̩ JAMB

Ẹ kò nílò nọńbà ìdánimọ̀ NIN fún ìdánwò àṣewọlé ọdún 2020… Àjọ JAMB Fẹ́mi Akínṣọlá Ni báyìí Àjọ tó ń rí sí ìdánwò àṣewọlé ilé ẹ̀kọ́ gíga JAMB tí kó àfàró nípa lílo nọ́mbà ìdánimọ̀ “NIN” fún ìdánwò àṣewọlé ọdún ...

Read More »

Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá

Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èsì àwọn ọmọ Nàìjíríà tó tẹ̀lé bí iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ṣe yin ara rẹ̀Lórí káàdì tí wọ́n fi síta lójú ...

Read More »

M C Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTW

MC Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTWLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíOro ti gbogbo ara ilu ni o ti ku regbe ti o si ti di ohun igbagbe ni o tun n rugbo ni ibere ise yii laarin Musiliu Akinsanya ati ...

Read More »