Home / Tag Archives: iroyin (page 8)

Tag Archives: iroyin

Mu pàrágá wakọ̀ l’Ọyọ, kóo kó sí páńpé̩ ìjọba

Omi tuntun ti rú, ẹja tuntun ti wọ ọ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Awakọ̀ mẹẹdọgbọn ni ọwọ́ òfin ti tẹ̀ nìpínlẹ̀ náà lórí ẹ̀sùn pé wọ́n ń mutÍ nígbà tí wọ́n tún ń wa ọkọ̀.

Read More »

Olè yabo báńkì: O fowó náà so̩dún Kérésì fáwọn èrò

Olè yabo báńkì. O fowó náà so̩dún Kérésì fáwọn èrò Bí ayé bá ń lọ sópin, àràǹbarà ìran lojú yóó máa rí. À bí kín ní ká tí pèyí sí pẹ̀lú bí arákùnrin òyìnbó onírungbọ̀ kan ṣe dédé yabo ilé ...

Read More »

Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì

Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ondo ti gbé Pásítọ̀ Alfa Babatunde tíí ṣe olùdásílẹ̀ Ìjọ Sòtítọbírẹ ní Ondo lọ Ilé ẹjọ́ léyìí tí ìwòye sì ...

Read More »

Ìròyìn Òwúrò̩ t’ò̩s̩è̩ yí

Read More »

Mo ti pàṣẹ fún àjọ DSS láti tẹ̀lé àṣẹ ilé ẹjọ́….Abubakar Malami

Ìjọba àpapọ̀ ti pàṣẹ pé kí wọ́n tú olùbádámọràn lóri ètò ààbò Sambo Dasuki àti agbétẹrù Revolution Now Omoyele Sowore silẹ̀ nínú àhámọ́.

Read More »

Ó di láyéláyé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè

Ó di láéláé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè Gbajúgbajà òṣèré Samuel Akinpẹlu tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àlàbí Yellow ti jẹ́ Ẹlẹ́dàá nípè. Akọni tí à ń perí yìí jẹ́ òṣèré tí àwọn èèyàn kò ...

Read More »

Àlùfá tọ́ bá ọmọ ọdún méje sùn, wẹ̀wọ̀n ọdún Márùn- ún ní ìpínlẹ̀ Ekiti

Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n t’olóhun.Ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti tífìtàn balẹ̀ bí wọ́n ṣe jẹ́ ìpínlẹ̀ àkọ́kọ́ tí yóò bẹ̀rẹ̀ láti máa dárúkọ ọ̀daràn afipá bánilòpọ̀ hàn àti láti máa dójú tì wọ́n. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Kayode Fayemi gbé ...

Read More »

Àhes̩o̩ ò̩rò̩ ni ikú Babangida

Aheso oro ni iku BabangidaYinka AlabiAriwo iku ajagunfehinti to o tun je Aare Ologun ni orileede yii tele ri, Ibrahim Babangida ni o gbode Kan.Ariwo yii po lori ero ayelujara lati idaji oni sugbon Ogbeni Kazim Afegbua ni iro ni. ...

Read More »

Iléeṣẹ́ DSS tú Sowore sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ gbọọrọ ní àhámọ́

Iléeṣẹ́ DSS tú Sowore sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ gbọọrọ ní àhámọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn òṣìṣẹ́ DSS gbé Soworẹ lásìkò tí ó fi ń léwájú ìwọ́de “Revolution now”.Ìtúsílẹ̀ rẹ̀ ń wáyé lẹ́yìn tí ó ti lo ọjọ́ márùndíláàdóje ní hàhámọ́ àwọn DSS. ...

Read More »

Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba – Seyi Makinde

Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ̀,wọ́n ní ,bí Ọlọ́run bá rí ọ, jéèyàn náà ó sẹ̀ríìrẹ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí,bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti fọwọ́ gbáyà pé òun ...

Read More »