Home / Tag Archives: Virus

Tag Archives: Virus

Ènìyàn mó̩kàndínlógójì ti ní àsepò̩ pèlú alárùn coronavirus l’Ogun

Iberu bojo ti po gan-an ni ipinle Ogun bayii, paapaa julo lati igba ti ayewo ti fihan pe alarun buruku kan ti wo orileede yii lati orileede Italy.

Read More »

Okùnrin ọmọ Italy kan ti kó àrùn Coronavirus wọ Nàìjíríà- Iléeṣẹ́ ètò ìlera

Okùnrin ọmọ Italy kan ti kó àrùn Coronavirus wọ Nàìjíríà- Iléeṣẹ́ ètò ìlera Iléeṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tó ń rí sí ìsàkóso àrùn ti sọ pé àrùn Coronavirus tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ COVID-19 ti tàn dé Nàìjíríà. Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ ...

Read More »