Home / Tag Archives: Yoruba

Tag Archives: Yoruba

Lakurubututu ! “Omo ya jo, omo le yeni”

Omolade,Omolowo,Omolola,Omo ni ola,Omoni’yi Omo’leye, Omolabake, Omolabage, Omopariola Omojowolo, Omosunbo, Omofowokade, Omofowokola Omotoriola, Omorinsola, Omorinsoye, Omobobola, Omoyosola Omoboboye, Omoyosade,Omoyosoye, Omodapomola, Omodapomoye Omoboriola, Omoboriola,Omotanshe,Omotanoshi, omo ju oun gbogbo lo, Aakun dabo ore wa toju omo re nitori awon ni Ojo ola re, ...

Read More »

Yoruba: How Top 3 Nigeria’s traditional rulers are selected (Yoruba)

Yoruba In Yoruba tradition, even though the position is hereditary, there are three to four families that are entitled to the throne. It is like a rotational system of government where rulership of a kingdom is circulated among the different ...

Read More »

Aworan Yii Kiise Aroso Rara !

Bi Mi O Tie Mo Iyawo, Sugbon Mo Mo Oko Pelu Ise-owo Re, Isele Aburu Yi Waye Ni Ilu Ilogbo Ota, Ni Ipinle Ogun. Oko (Morufu Olasoji) Nfi Esun Agbere Kan Iyawo Re Kehinde Olasoji, Pelu Igbonara, Oko Lu Iyawo ...

Read More »

Grandson Blows Hot Again! Hotter Actually!!

Lets hear your thoughts in the comment box bellow.

Read More »

E ku ojumo eyin omo ile kaaro ojiire. Se daada ni?

Mo gba l’adura wipe bi a tin jade lo fun ise oojo wa, ao ni ko el’esu l’ona. Iko ki n ko ejo l’ese, ayun lo ayun bo l’owo n yun enu. Atepe ni ese n te’na. Ire ila oorun, ...

Read More »

kini yoruba mape oruko kini yi

Read More »

Gbogbo ona loti baje !

O dabi ala loju mi ni, mo gbe ero alupupu ti mo sese ra lati ma gbe losi ayika ile Olorun, nitiripe gbogbo ona loti baje, moto ko rorun tabi ya lara lati gbe jade, mo gun ero alupupu naa ...

Read More »