Home / Aarin Buzi / Ori iya mi ooooo! Ukwu ore Yemi Alade ti da gobe sile o.

Ori iya mi ooooo! Ukwu ore Yemi Alade ti da gobe sile o.

Wahala ti bere si ni sele lori ayelukara bayii, eleyii si bere nikete ti Yemi Alade se afihan foto re pelu awon ore, eni to se apejuwe won gege awon ololufe orin re. Awon eniyan ko tile soro nipa Yemi Alade, “apoti aje” ti ore re gbe seyin gan-angan lo fa rigimo oun surutu bayii.

olayemioniroyin.com

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*