Home / Àṣà Oòduà / Èmi ò kì ń s̩e “His Excellency” – Sanwo-olu

Èmi ò kì ń s̩e “His Excellency” – Sanwo-olu

Ogbeni Babajide Sanwo-olu ni mi. Mi o ki n n se “His excellency”.
Gomina ipinle Eko lo n salaye yii fun awon oniroyin lonii ojo kefa osu kokanla odun yii.
Gomina ni igberaga wa ninu oruko ” His Excellency “. E saa maa pe emi ni “Mr Governor “.
Gomina ni iwe iso-di-ooto re gan-an maa jade ni ola, ojo keje, osu ti a wa ninu re yii.

About ayangalu