Category: Àṣà Oòduà
-
Osinbajo wọ́gilé ìrìn-àjò rẹ̀ lẹ́yìn tí ọ̀kan lára ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ kú lọ́nà pápákọ̀ òfurufú
Osinbajo wọ́gilé ìrìn-àjò rẹ̀ lẹ́yìn tí ọ̀kan lára ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ kú lọ́nà pápákọ̀ òfurufú Ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ṣọ́ ìgbákejì Ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo sàgbákò ikú ójijì nínú ìjàmbá alùpùpù lọ́jọ́ Ẹtì. Ali Gómìnà, tó jẹ́ ọlọ́pàá rìpẹ́tọ̀ gbẹ́mì ín mì nínú ìjàmbá náà tó ṣẹlẹ̀ lọ́nà pápákọ̀ òfurufú Nnamdi Azikiwe nílùú Abuja. Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀…
-
Fayemi, ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) kìí ṣe Kano tí wọn ti ń yọ Emir lórí oyè… Alaafin
Àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí ojú òpó ìkànsíraẹni Twitter ti dásí ọ̀rọ̀ láàrin Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti, Kayode Fayemi àti àwọn ọba ní ìpínlẹ̀ náà. Èyí kò sẹ́yìn lẹ́tà tó jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi Kẹta ti kìlọ̀ fún gómìnà ìpínlẹ̀ Ekiti láti ṣọ́ra ṣe, ki o si tẹlẹ jẹjẹ.…
-
Òhun tí Ọlọ́run ṣe fúnmi ju n tó tọ́ sí mi lọ— Ọbasanjọ
Òhun tí Ọlọ́run ṣe fúnmi ju n tó tọ́ sí mi lọ— Ọbasanjọ Olóyè Ọbasanjọ, gẹ́gẹ́ bí ara ètò fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún kẹtàlélọ́gọ́rin rẹ̀ léwájú àwọn èèkàn lọ síbi àpèjẹ pàtàkì kan fún àwọn àlejò gbogbo. Olóyè Ọbasanjọ pé ẹni ọdún mẹtàlélọ́gọ́rin ní ọjọ́ karùn- ún oṣù kẹta ọdún 2020. Òdú ni Olóyè…
-
Gómìnà Kaduna, El-Rufai fi ipò kejì dá Sanusi lọlá láàrin ọjọ́ méjì
Wọ́n fikún un pé àwọn gbé ìgbésẹ̀ náà nítorí wọ́n mọ pé ìpínlẹ̀ Kaduna yóó rí ohun ribiribi kọ́ lára ọgbọ́n tí Sanusi ní àti òye rẹ̀ nípa ètò ọrọ̀ ajé.
-
Ado Bayero di Emir Kano
Adi Bayero di Emir Kano Ìdààmú ilé ọlá kan kìí rọ̀, ko ko ko níí le. Ní báyìí Ìgbìmọ̀ ìsàkóso Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti rọ Emir Sanusi lóyè ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kẹsàn án Oṣù kẹta ọdún 2020. . Ó ti tó ọjọ́ mẹ́ta kan tí gbún-gbùn-gbún ti ń wáyé láàrin gómìnà ìpínlẹ̀ Kano, Abdullahi…
-
Ọ̀ràn dé! Alárùn coronavirus di méjì ní Nàìjíríà
Lara ayewo ti ijoba apapo ati awon ajo NCDC (Nigeria Centre for Disease Control) n se pelu awon ti won ba arakunrin ara orileede Italy wo baalu ati oko po. Won n se ayewo yii naa pelu awon ti won jo se ipade ni ilu Ewekoro to wa ni ipinle Ogun. Ileese Lafarge Cement Plant…
-
Ganduje ti rọ Emir ìlúu Kánò, Sanusi Lamido Sanusi lóyè
Ganduje ti rọ Emir ìlúu Kánò, Sanusi Lamido Sanusi lóyè Ìdààmú ilé ọlá kan kìí rọ̀, ko ko ko níí le. Ní báyìí Ìgbìmọ̀ ìsàkóso Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti rọ Emir Sanusi lóyè ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kẹsàn án Oṣù kẹta ọdún 2020. . Ó ti tó ọjọ́ mẹ́ta kan tí gbún-gbùn-gbún ti ń wáyé…