Home / Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, ...

Read More »
Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?

Read More »

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò ...

Read More »
sibeki

Àjọ EFCC ti ń wá àwọn tó wà nídìí ṣogúndogójì CBEX

Èyí ni àwòrán mẹ́rin nínú àwọn tó wà nídìí ṣogúndogójì CBEX. Àjọ EFCC ti ń wá wọn

Read More »
Kààkàkí Oba

Ẹ̀yin ojúlówó ọmọ Yorùbá àtàtà dà?

Ǹjẹ́ ẹ mọ orúkọ tí Yorùbá ń pe ohun ti Bàbá yìí ń fọn?

Read More »
Bí Ẹ Bá Rí Ilá L'ọ́jà Kí Ẹ Ma Rà Fún Mi

Bí Ẹ Bá Rí Ilá L’ọ́jà Kí Ẹ Ma Rà Fún Mi

Mo ní èmi ò fẹ́Mo ní èmi ò jẹBí ẹ bá rí ikàn l’ọ́jà kí ẹ ma rà fún miMo ní èmi ò fẹ́Mo ní èmi ò jẹAtẹ̀gbẹ̀ tí o bá délé Olódùmarè kí o ra ọmọ wẹrẹ wá fún ...

Read More »
Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé ...

Read More »
abinibi

Ede Abinibi

Read More »

Osa Esu

Osalogbe Awo ApalaOsalogbe Awo ApalaaAdifafun Orunmila AjanaBaba Yoofi Oro jagbajagb’a ro Sorun EsuBabagbeboBabaruboEsu Odara ti n ba Ni Owo lowo Odorun re Esu Odara Odorun reEsu Odara ti n bani Aya Odorun re Esu Odara Odorun reTi n ba bimoTi ...

Read More »
Yemọja

ÉÉPà Omi O!!!grand Finale, Yemọja ÒGùnlẹ́kí – Pópó Yemọja, Ìbàdàn

A dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ Baálẹ̀ Yemọja, Ìyá Omítọ̀nàdé, Ẹbí, Ará, gbogbo Àgbà àti Ọmọdé… Ìbà Olódùmarè, ọdún pé, ọdún jọ. .To all friends, fans and well wishers, we’re grateful.

Read More »