Category: Àṣà Oòduà
-
Pa Kasumu, ó dìgbà kan ná
Kayode Odumosu,papòdà lẹ́ni ọdún mẹ́tàdínláàdọ́rin Gbajúgbajà òṣèré tíátà Kayode Odumosu tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Pa Kasumu ti juwọ́ ìgbẹyìn sáyé pé ó dìgbàkan. ”Èèyàn dáadáa ni wọ́n yàtọ̀ sí pé wọ́n jẹ́ òṣèré tíátà.Ikú wọ́n jẹ́ eléyìí tó fi ọ̀kọ̀ọ̀kan wa lẹ́mìí” Yàtọ sí Mr Latin àwọn òṣèré míràn bí Foluke Daramola ti fi…
-
Omijé bọ́ lójú ù mi nígbà tí mo rí olóògbé Pa Kasumu gbẹ̀yìn.—Olóyè Lere Pàímọ́
Omijé bọ́ lójú ù mi nígbà tí mo rí olóògbé Pa Kasumu gbẹ̀yìn.—Olóyè Lere Pàímọ́ Bá a pẹ́ tí tí, bí ẹni rebi,bi èmi sì gùn gùn gùn bí okùn tó gùn,ikú lòpin èèyàn.Ìjọ aláyé ti dáyé, lakásọlérí ti í ṣunkún ara a wọn, kò ṣẹ́ni tí ò níí kú, kò ṣẹ́ni tí oko baba…
-
Okùnrin ọmọ Italy kan ti kó àrùn Coronavirus wọ Nàìjíríà- Iléeṣẹ́ ètò ìlera
Okùnrin ọmọ Italy kan ti kó àrùn Coronavirus wọ Nàìjíríà- Iléeṣẹ́ ètò ìlera Iléeṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tó ń rí sí ìsàkóso àrùn ti sọ pé àrùn Coronavirus tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ COVID-19 ti tàn dé Nàìjíríà. Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tó fi léde lójú òpó Twitter rẹ̀, ó ní “Mínísítà fún ètò ìlera ti fi…
-
Ìjàm̀bá iná se ò̩nà Eko sí Ibadan ati Ibadan sí Eko pa
Ìjàm̀bá iná se ò̩nà Eko sí Ibadan ati Ibadan sí Eko paÌròyìn láti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíOro gbogbo kii se lori alabahun ni opopona Eko si Ibadan ati Ibadan si Eko. Lati igba ti awon Julius Berger ti bere ona naa ni titun se ni isolenu re ti po sii. Ijeeje to o koja yii ni…
-
Sofia Kenin gba ife è̩ye̩ ìdíje Australia open 2030
Omo orileede American, Sofia Kenin, ti fi ebun re han si gbogbo agbaye pelu bi o se bori ifigagbaga asekagba laarin oun ati omo orileede Spain
-
Akiyesi Pataki
Arákùnrin oníṣègùn oyinbo tó jẹ́ ọmọ bíbí Nigeria to wá n’ilu USA, fi ọrọ ìyànjú yí ranṣẹ fún anfaani ara wa. Jọ̀wọ́ ká, kí ó sì mú lo fún ìtọ́jú ara rẹ. Dr. A. Malgwi Ọna ti àwọn ọdọ wá lóde òní, ngba ni àìsàn kidirin jẹ ohun tó ndẹru báni. Mo nfi itẹjade yí…
-
Sanwo-olu dáhùn ìbéèrè okada ló̩wó̩ aké̩kò̩ó̩ Chrisland
Sanwo-olu dáhùn ìbéèrè okada ló̩wó̩ aké̩kò̩ó̩ Chrisland Láti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíGomina Babajide Sanwo-olu ti ipinle Eko lo n dahun orisiirisii ibeere lowo awon akekoo ile-iwe Chrisland to wa ni ilu Opebi ni Eko, nigba ti o gba won lalejo ni oni ojo kokanlelogbon, osu kin-in-ni odun yii. Gomina ni ilekun oun si sile fun omode…