Category: Àṣà Oòduà
-
È̩ ń fi ẹ̀wọ̀n run imú ẹ̀yin Olóyè Ìbàdàn mọ́kànlélógún tẹ ń ǹ pera a yín lọ́ba
Ọrọ̀ kò tíì tán lórí àwọn Olóyè mọ́kànlélógún tí Ilé ẹjọ́ sọ pé kí wọ́n lọ rọọ́kún nílé nílùú Ìbàdàn. Kọmíṣọ́nnà ètò ìdájọ́ tẹ́lẹ̀rí nípìńlẹ̀ Oyo, Ọ̀gbẹ́ni Michael Lànà ló ṣe ìkìlọ̀ fún wọn pé, kí wọ́n yé pe ara wọn ní ọba káàkiri, bí bẹ́ẹ̀kọ́, wọ́n ń fi ẹ̀wọ̀n run imú ni. Nínú àtẹ̀jáde…
-
Àmọ̀tẹ́kùn: Ẹ̀ṣọ́ ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) ‘Àmọ̀tẹ́kùn’ ṣetán láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ káàkiri ilẹ̀ káàárọ̀ o ò jíire
Ọ̀rọ̀ ti di olójú ò níí yajú ẹ̀ sílẹ̀ kí tàlùbọ̀ ó yíwọ̀ọ́ àti pé ọmọ onílùú kò níí fẹ́ ó tú lọ̀rọ̀ dà báyìí ó, bí.
-
Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn
Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn Fẹ́mi Akínṣọlá Erin wo! Àràbà Awo ilẹ̀ Ìbàdàn, Ògbó Awo Oyewusi Amọo Fakayode wọ káàl’ẹ̀ sùn.Ọjọ́ a kú là á dère,èèyàn ò sunwọ̀n láàyè. Bí àlá ló ń ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹni ọ̀rọ̀ kàn nílànà ìṣẹ̀ṣe nígbà tí wọ́n gbọ pé àgbà awo náà tí jawàá lẹ̀.Ògbó…
-
Ìjọ Ọ̀rúnmìlà Ifákáyéjọ afi òtítọ́ ayé hàn
Àwa ni ìmọ́lẹ̀ fún gbogbo Ìjọ mímọ́ Ọ̀rúnmìlà ní gbogbo àgbáyé nítorí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí àńpè ní Ifá ni a fín to Ìjọ tiwa Ifá(ọ̀rọ̀ Ọlọ́run)ni afi kó ayé jọỌ̀rúnmìlà(aṣíwájú rere)ní abá ni táyése Ẹ wá bá ọ̀rọ̀ ẹnu Ọlọ́run tí àńpè ní Ifá pàdé nínú ìjọ wa, kí ìtumọ̀ sí bá ìgbésí ayé rẹ…
-
Òlódumarè les bendiga, que tengan una feliz y bendecida tarde.
Ẹ̀là mo yìn bọrú.Ẹ̀là mo yìn bọyè.Ẹ̀là mo yìn bọ’ṣíṣẹ. Òlódumarè les bendiga, que tengan una feliz y bendecida tarde. Ijuba. Doy reverencia. Ìdà kí si ònà ní nse ejó lè yínA’dífá’fún Esin ohun AgboTi wòn nse Awo losí ilé oní AlákétuNjó tó jí ti kò ojúnbà BàbáTi kò ojúnbà YèyéÌbà BàbáÌbà YèyéÌbà OlówòÌbà Ojù’gb’ònà……Ìbà…
-
Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan
Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan Ààrẹ Buhari ti pe Ààrẹ àná, Goodluck Jonathan lórí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀,láti báa kẹ́dùn lórí ìkọlù àwọn agbébọn tó wáyé ní Òtuòkè tíí ṣe ìlú abínibí rẹ̀ nípìńlẹ̀ Bayelsa. Nínú ọ̀rọ̀ orí fóònù náà, Ààrẹ Buhari kò fi bí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣe ba òun nínú…