Category: Àṣà Oòduà
-
Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èsì àwọn ọmọ Nàìjíríà tó tẹ̀lé bí iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ṣe yin ara rẹ̀Lórí káàdì tí wọ́n fi síta lójú òpó ayélujára Twitter wọn, iléeṣẹ́ ọlọ́pàá sọ pé káàdì náà jẹ́ àfihàn àkójọpọ̀ àwọn àṣeyọrí…
-
Iyami And Ipese To Appease Iyami
The Iyami are supernatural women who have been blessed by Elodumare with a great power which can be seen in the Odu Ifa Osetua, where it is written: anyone who makes a plan by excluding from it the ideas of the women, must know that their plan is intended to fail.
-
Transforming Ìṣẹ̀ṣe Temples, Shrines, Houses Of Worship
Women devotees live in a sanctuary that attends to both their spiritual and physical needs at the Àkòdì Òrìṣà. We train them to produce things that can be marketed. Spirituality is great and necessary. But we also have material needs—which is what the colonizers realized when they brought Christianity and Islam: they built churches, while…
-
M C Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTW
MC Oluo̩mo̩ fo̩wó̩ o̩lá gbáwa lójú – NURTWLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíOro ti gbogbo ara ilu ni o ti ku regbe ti o si ti di ohun igbagbe ni o tun n rugbo ni ibere ise yii laarin Musiliu Akinsanya ati Adekunle Lawal ti gbogbo eniyan mo si Kunle Poly. Ikolura-eni yi ti n rugbo bo…
-
Àwọn ará ilú dáná sún èèyàn méjì tí wọ́n furasí bíi olè
Àwọn ará ilú dáná sún èèyàn méjì tí wọ́n furasí bíi olè Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n tolóhun.Àwọn ènìyàn méjì kan ti wọ́n fura si gẹ́gẹ́ bi olè, ni wọ́n ti dáná sun nílùú Calabar, tíí ṣe olú ilú Cross River. Ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé ní agbègbè Akai Effa, tíwọ́n sì fi tipá fún…
-
Ẹgbẹ́ Shiites wọ́de l’Abuja, wọ́n jó Àsìá Amẹ́ríkà
Ẹgbẹ́ Shiites wọ́de l’Abuja, wọ́n jó Àsìá Amẹ́ríkà Egbìnrìn ọ̀tẹ̀, bá a se n pàkan, nìkan ń rúÀwọ́n ọmọ ẹgbẹ́ “Islamic Movement of Naigeria” (IMN) tí gbogbo ènìyàn mọ sí Shi’ites lọ́jọ́ ajé ti ya sí ìgboro lágbègbè ilé ìtajà Bannex ni Wuse nílú Abuja láti wọ́de nítorí Olórí ọmọ ogun Iran Quasm Soleimani ti…
-
Ẹjẹ yóó sàn, bí Amẹ́ríkà ṣe pa olórí ọmọ ogun un wa – lran
Ẹjẹ yóó sàn, bí Amẹ́ríkà ṣe pa olórí ọmọ ogun un wa..lran Kójú má ríbi , gbogbo ara lòògùn rẹ̀,bó ṣe jẹ́ pé, ó ń bọ̀ ,ó ń bọ̀ , gbogbo ara ní wọ́n mú tó o.À bí kí lọ̀rọ̀ ogun abẹ́lé kẹta “World War III”ṣe tan mọ́ ikú olórí ọmọ ogun Iran tó kú?Àwọn…