Category: Àṣà Oòduà
-
Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’
Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ ló kò yìí, kín làkíyèsí ẹ̀yin obìnrin lórí àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn Fẹ́mi Akínṣọlá Ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹwàá ọdọọdún ni àyájọ́ ọjọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ lorilẹede Nàìjíríà eyi tó ń sọ fún àwọn obìnrin láti bá kọ́mú yan odì lọ́jọ́ náà. Gẹ́gẹ́ báa ṣe mọ̀ oṣù Kẹwàá yìí kan náà ní àwùjọ…
-
Ìjọba ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní gbowó orí lóri ìbáraẹnisọ̀rọ̀
Ìjọba ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní gbowó orí lóri ìbáraẹnisọ̀rọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àbùùbùtán oore lọ̀rọ̀ sísọ jẹ́ ,fáwa ọmọ aádámọ̀,ọ̀làjú àsìkó yìí,ti fẹ́ mú kí nǹkan ó gbọ̀nà ọ̀tun yọ,bí ó ti jẹ́ pé ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ orílẹ̀èdè yìí yóò máa same lórí ìpè e won.Álága ilé iṣẹ́ tó…
-
Soworẹ́ Gbòmìnira Láhàmọ́ Ọ́ Dss Pẹ̀lú Ọgọ́rùn Ún Mílíọ̀nù Náírà
Soworẹ́ gbòmìnira láhàmọ́ ọ́ DSS pẹ̀lú ọgọ́rùn ún mílíọ̀nù náírà Fẹ́mi Akínṣọlá Èèyàn téégún ń lé,kó máa rọ́jú,bó ṣe ń rẹ ará ayé,náà ló ń rèrò ọ̀run. Àgbálọ gbábọ̀, ilé ẹjọ́ gíga t’ìjọba àpapọ̀ l’Abuja ti gba béèlì Omoyele Soworẹ́ to ṣagbatẹru iwọde “Revolution Now”.Ọgọrun un miliọnu náírà ni ilé ẹjọ́ fi fun Soworẹ́ ni…