Category: Àṣà Oòduà
-
Èmi kò fé̩ràn láti máa fe̩nu ko obìnrin lé̩nu nínú eré – Taiwo Hassan
Taiwo Hassan Ọlọ́jọ́ọ̀bí, akọni òṣèré Yollywood tó dáńtọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Yoòbá bọ̀, wọ́n ní èèyàn tó bá monú-ún rò, ọpẹ́ ẹ rẹ̀ yóó lékún bóyá n ló fa sábàbí bí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ọmọ Nàìjíríà ti ń darapọ̀ kí àgbà òṣèré Taiwo Hassan kú oríire ọgọ́ta ọdún lórílẹ̀ eèpẹ̀ báyìí. Yinka Quadri tó jẹ́ ọ̀rẹ́ tí wọ́n…
-
Oríkì Obàtálá
Ọbàtálá ọbátárìsàỌba pátápátá tí ń bá wọn gbóde iránjéỌba nílé Ifọ́nÒ sùn nínú àlàÒ jí nínú àlàÒ tí inú àlà dìdeÒrìṣà wun mi ní budoIbi Ire l’òrìsá kalẹ Akú òsè Obàtálá O
-
Ẹ ẹ̀ ṣi nọ́ńbà mú l’Ọyọ, gbogbo owó yín tí mo bá ná, ẹ ó rí n tí mo fi se – Seyi Makinde
Ẹ ẹ̀ ṣi nọ́ńbà mú l’Ọyọ, gbogbo owó yín tí mo bá ná, ẹ ó rí n tí mo fi se…..Seyi Makinde Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí Ọlọ́run bá sẹ̀rí ì rẹ,jẹ́ kí èèyàn náà ó sẹ̀rí ì rẹ .Gomina ìpínlẹ̀ Ọyọ, Onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde tún ti fọwọ́ méjéèjì sọ̀yà fún àwọn olùgbé…
-
Àsírí Òkété
ÒKÉTÉ.___Òkété jẹ́ ọ̀kan nínú ẹranko abàmì tó lágbára púpọ̀. A sì máa gbé nínú ihò. ELÉDÙMARÈ fún-un ní àṣẹ púpọ̀.Òkété kìí fi ọwọ́ tàbí ẹṣẹ̀ gbẹ́ ihò, ÌRÙ ni òkété maá n fií gbẹ́ ihò, fún ìdí èyí, ẹ ò le rí èrùpẹ̀ lẹ́nu isà òkété, bí ènìyàn bá gbẹ́ ihò òkété, ìgbà mìíràn a…
-
Iṣẹ́ ìránṣẹ́ kò sí fún ìmẹ́lẹ́ èèyàn – Tunde Bakare
Fẹ́mi Akínṣọlá Ayé ló bàjẹ́ tí ọmọ olè ń dájọ; oníkálukú mọ ẹ̀tọ́ tó yẹ́’.Olùṣọ́ àgùtàn Tunde Bakare ṣàlàyé bí ìdámẹ́wàá ṣe bẹ̀rẹ̀ ninu Bíbélì àti pé kò si ẹni tí wọ́n gbé ìbọn tì pé dandan ni kó san ìdámẹ́wàá.Ó ní iṣẹ́ ọwọ́ òun ni òun ń jẹ nítorí pé Ọlọ́run kìí pe ọ̀lẹ…