Category: Àṣà Oòduà
-
Àmọ̀tẹkùn ni wọn yóó maa pe orúkọ ikọ̀ tó n pèsè ààbò yíká ilẹ̀ Yorùbá – Akeredolu
Àmọ̀tẹkùn ni wọn yóó maa pe orúkọ ikọ̀ tó n pèsè ààbò yíká ilẹ̀ Yorùbá…..Akerdolu Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe Yoruba bọ ,wọn ni Ogun ti yoo wọle koni,ọna la a tii pade ẹ lo bi ọrọ ti Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu sọ,bi o ṣe kede pe Amotẹkun ni wọn yoo maa pe orukọ ikọ to…
-
Adúmáadán Àjèjé
Ẹmu daada ní ń bẹ nínú aháÒgùrọ̀ àtàtà ní ń bẹ nílẹ̀ akèrèǹgbèỌtí ò dá, àlejò ò lọ!Ẹni ọtí kìí tí AdúmáadánAdúmáadán Àjèjémá gbádùn ara rẹ lọ! ‘Òògùn ibà ni, òògùn ibà ni,’Bí eré, bí eré ìyálé ilé mútí yó!Ẹmu lásán ni kìí pàayànÀṣẹ̀yínwá àṣẹ̀yìnbọ̀ baálé ń tọ̀ sí ṣòkòtò.Akúwárápá abitọ́ funfun lẹ́nu.Èpè akèǹgbè ọmọ…
-
Odù Ifá Mímọ́ Ọ̀bàrà Bubu
Ekáàrọ̀ọ́ ẹ̀yin ènìyàn mi, aojiire bi? Oni a sanwa o, ao rí tiwa se loni, gẹ́gẹ́bí òní ṣe jẹ ọjọ́ àíkú, gbogbo wa koni kánjú ku lágbára Olodùmarè àṣẹ.E jékí a fi odù ifá mímọ́ ọ̀bàrà bubu yi ṣe ìwúre ti aarọ yìí.Ifá náà ki báyì wípé:Òkún ṣànÓ relé òkunÒsá ṣànÓ relé ọ̀sàÓní Alárá nwọ…
-
Fayose kò mo̩ bò̩ò̩lì àti àgbàdo je̩ tó mi,àmó̩… – Fayemi
Gomina ipinle Ekiti, Dr Kayode Fayemi lo n salaye yii nibi eto ori telifison Kan ti arabinrin Morayo Afolabi n dari re. Leyin ti gomina dahun orisiirisii ibeere ni arabinrin naa wa tun beere asepo to wa laarin oun ati gomina ana ni ipinle naa, Alagba Ayodele Fayose.Fayemi ni asepo to dan moran wa laarin…
-
Gege bi Omo Oodua Rere, Nje E Mo Oruko ti won pe kokoro yi ?
Kini Oruko ti won pe kokoro ti o wa ninu aworan oke yii ?
-
E fun mi ni owe to ni Ile(house) ninu ?
Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu. E seun.