Home / Awọn Iroyin Agbegbe

Awọn Iroyin Agbegbe

À ń fún àwọn èèyàn lọ́rùn pa ni-Monsuru Afurasí

À ń fún àwọn èèyàn lọ́rùn pa ni-Monsuru Afurasí Fẹ́mi Akínṣọlá Àtubọ̀tán ayé ń kànkùn gbọ̀ngbọ̀n.Àwọn àgbà bọ̀, wọ́n ní bí a bá ń rin ìrìnàjò, kí á wo ẹni tí à ń bá lọ, nítorí àti ilé àti òde ...

Read More »
endsars

Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́ṣì fèsì lórí ìwọ́de EndSARS

Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́ṣì fèsì lórí ìwọ́de EndSARS Fẹ́mi Akínṣọlá Ìjọba orílẹ̀-èdè United Kingdom, ti fèsì lórí ìwé ẹ̀sùn tí àwọn ọmọ Nàìjíríà fọwọ́ sí, tí wọ́n sì fi ránṣẹ́ síi. Ìwé náà ló ń ké sí àwọn orílẹ̀-èdè àgbáyé tó wà ...

Read More »
Amotekun

Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ kéde orúkọ àwọn aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn rẹ̀

Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ kéde orúkọ àwọn aláàbò Àmọ̀tẹ́kùn rẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Olójú kò nì-ín lajúẹ̀ sílẹ̀, kí tàlùbọ̀ ó yí wọ̀ọ́. Bẹ́ẹ̀ ni bí èèyàn bá joyè Arẹ̀kú, ó yẹ kó lè pitú lábẹ́ agọ̀. Èyí ló mú kí àwọn ìjọba ...

Read More »

EndSARS: Olórí ilé aṣojú-ṣòfin ní ìṣúnà 2020 gbọdọ̀ pèsè owó fún ASUU bí bẹ́ẹ́kọ̀…

EndSARS: Olórí ilé aṣojú-ṣòfin ní ìṣúnà 2020 gbọdọ̀ pèsè owó fún ASUU bí bẹ́ẹ́kọ̀… Fẹ́mi Akínṣọlá Olórí ilé asojú-sòfin nílẹ̀ wa, Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà ti sòṛọ̀ nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó se kókó tó n wáyé nílẹ̀ wa, paàpá ìwọ́de EndSARS. Gbàjàbíàmílà, ...

Read More »
janduku

Jàǹdùkú pa ọlọ́pàá méjì, jó àgọ́ wọn mẹ́wàá, báńkì mẹ́ta, jí ọ̀pọ̀ owó l’Ékó -iléeṣẹ́ ọlọ́pàá

Jàǹdùkú pa ọlọ́pàá méjì, jó àgọ́ wọn mẹ́wàá, báńkì mẹ́ta, jí ọ̀pọ̀ owó l’Ékó -iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, ìjàngbọ̀n kìí dúró síbi tó bá rọ̀, bí kò ṣe ibi tó bá le koko. Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ...

Read More »
sanwo

Ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki, Ẹ̀ẹ̀mejì ni mo pe Ààrẹ Buhari lánàá , àmọ́ ń kò ri bá sọ̀rọ̀ – Sanwo-Olu

Ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki, Ẹ̀ẹ̀mejì ni mo pe Ààrẹ Buhari lánàá , àmọ́ ń kò ri bá sọ̀rọ̀ – Sanwo-Olu Fẹ́mi Akínṣọlá Bí ọ̀rọ̀ ńlá kò bá tíì tán èèyàn ńlá kò ní tíì sinmi àròyé Sanwo-Olu tíí se Gómìnà wọn ní ...

Read More »

Ìdí tí nó̩ḿbà ìdánimò̩ kò fi jé̩ dandan mó̩ – Àjo̩ JAMB

Ẹ kò nílò nọńbà ìdánimọ̀ NIN fún ìdánwò àṣewọlé ọdún 2020… Àjọ JAMB Fẹ́mi Akínṣọlá Ni báyìí Àjọ tó ń rí sí ìdánwò àṣewọlé ilé ẹ̀kọ́ gíga JAMB tí kó àfàró nípa lílo nọ́mbà ìdánimọ̀ “NIN” fún ìdánwò àṣewọlé ọdún ...

Read More »

Iléeṣẹ́ DSS tú Sowore sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ gbọọrọ ní àhámọ́

Iléeṣẹ́ DSS tú Sowore sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ gbọọrọ ní àhámọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn òṣìṣẹ́ DSS gbé Soworẹ lásìkò tí ó fi ń léwájú ìwọ́de “Revolution now”.Ìtúsílẹ̀ rẹ̀ ń wáyé lẹ́yìn tí ó ti lo ọjọ́ márùndíláàdóje ní hàhámọ́ àwọn DSS. ...

Read More »

Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba – Seyi Makinde

Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ̀,wọ́n ní ,bí Ọlọ́run bá rí ọ, jéèyàn náà ó sẹ̀ríìrẹ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí,bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti fọwọ́ gbáyà pé òun ...

Read More »

Atiku tún pàdánu nílé e̩jó̩ tó ga jù

Atijo tun padanu nile ejo to ga juLati owoYinka AlabiIle-ejo to ga ju lo ni orileede yii ti se idajo lori ejo ti oludije dupo Aare ni abe egbe oselu PDP, Alhaji Atiku Abubakar.Ile-ejo ni Aare Muhammadu Buhari naa ni ...

Read More »