Category: Àṣà Oòduà
-
Akékòó okùnrin tí ó ti wà ní ìpelè tí ó parí ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìlú Oko ni won yìnbo fún tí ó sì kú.
Arákùnrin kan ni won yìn ìbon fún ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìjoba ní Oko ní ìpínlè Anambra. Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé tí gbogbo èèyàn mò sí ‘ De moon’ jé Akékòó féè pari tí ó sì jé wípé odún yí ni yóò parí èkó rè, ni won ti yin ìbon fún ní…
-
Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú.
Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú. Gbajúgbajà olórin àti ìlú mòóká olórin tí gbogbo ayé mò sí Wizkid àti Kiss Daniel ya àwòrán papò nínú okò ojú òfurufú aládani. Nse ni ó dàbí eni wípé won fé jo ko orin tí yóò mìlú tìtì papò. Nse ni ó dàbí eni wípé òré…
-
Toke Makinwa nínú aso ìwè nígbà tí ó lo sí èbá òkun ní ìlú Èkó.
Gbajúgbajà ò n lò èro ayélujára tí a mò sí Toke Makinwa tí gbé ògo tí olórun fún hàn, nígbà tí ó gbé àwòrán ìgbà tí ó wo aso ìwè sí orí èro ayélujára tí ó n jé Ínsítágírámù . Àwòrán tí ó gbòde yí ni ó yà ní èbá òkun ní ìlú Èkó. Toke…
-
Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour.
Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour. Gégé bí òrò ata díndín tí ó gbòde kan, òrò nípa Tiwa Savage àti Wizkid tí àwon èèyàn n gbà, tí won sì n je lénu, Yemi Alade àti Flavour náà ti se ti won tí won pè…
-
Ogbè Ògúndá (Ogbèyọ́nú)
Ifá pé òun yóò ṣe oore òjijì fún ọmọ Ogbèyọ́nú tàbí ẹni yòówù tí a dáfá yìí fún. Ifá pé ìgbàgbọ́ rẹ̀ kò tó nǹkan nínú òun; pé kó lọ ní ìgbàgbọ́ tó jinlẹ̀ síwájú síi nínú òun Ọ̀rúnmìlà. Ifá pé kí ó máa ṣèbọ fún òun ní ìgbà kú gbà tí ojú bá ti…
-
Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè.
Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè. Oònirìsà ti jé kí á mò wípé yèyélúwà kò te èjè mólè rárá àti wípé Osùn ni Oluwaseyi Moronke, Yèyélúwà tuntun tè mólè kìí se èjè rárá. Oba Adeyeye Enitan Babatunde omo Ogunwusi ti jé kí ó di…
-
Kò kò, ó gbà láti se ètùtù, Moronke Naomi Oluwaseyi gbà láti se òun tótó gégé bí olorì àkókó láàrin àwon olorì pátápátá.
Bí won se ni kó se é ló se é. Bí ó tilè jé wípé àtúnbí nínú Jésú ni, kò kò láti se àwon ohun tí ó tó gégé bí olorì láàfin Oòni ti ilé-ifè. Àwòrán ibi tí ìyàwó ti n se àwon ètùtú tí ó ye, tí ó sì dá èjè kojá. Àdúrà wa…
-
Bí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun.
Bí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun. Sùúrù tí ó lójó ni Omo Ogunwusi fi se, Aláse èkejì Òrìsà so Naomi Oluwaseyi Silekunola di Olorì láàfin rè. Èyin omo odùduwà e kú orí re. Yèyélúwà káàbò sí Àafin Oònirìsà. Adeyeye Enitan Ogunwusi a ki yín kú…
-
Alex Asogwa di onílè púpò ní Omo odún méjìlélógún (22).
Ará ilé Big Brother Naija télè tí a mò sí Alex Asogwa tí ó sèsè towó bo ìwé pèlú ilé-isé tí ó n ta ilè tí ó tún ń ta Ilé, ilé-isé real estate and investment company.Alex Asogwa ti gbe lo sí orí èro ayélujára láti dúpé lówó olórun, nítorí kìí se onílè eyo kan…
-
KÍ LÓ BÀJẸ́ LÉDÈ WA
Ẹ jẹ́ kí a tibi pẹlẹbẹ mú ọ̀lẹ̀lẹ̀ jẹ. N jẹ́ fífi gẹ̀ẹ́sì kọ́ni lédè Yorùbá le múni yege dáada nínú ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá bí? Gẹ́gẹ́ bíi òwe gẹ̀ẹ́sì kan tí ó wí pé, “the best way to understand a language is by speaking it” Ọ̀NA KAN GBÒÓGÌ TÍ A FI LE GBỌ́ ÈDÈ KAN…