Home / Àṣà Oòduà / Bí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun.

Bí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun.

Bí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun.
Sùúrù tí ó lójó ni Omo Ogunwusi fi se, Aláse èkejì Òrìsà so Naomi Oluwaseyi Silekunola di Olorì láàfin rè. Èyin omo odùduwà e kú orí re.
Yèyélúwà káàbò sí Àafin Oònirìsà. Adeyeye Enitan Ogunwusi a ki yín kú oríre, Aya rere ni Yeyeluwa yóò jé.
Ó dun tó béè gé, ìyá aláàdúrà di aya Oòni ti ilè ifè.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo