Category: Àṣà Oòduà
-
Ìjọba àpapọ̀: À nì sẹ́, dan dan l’óúnjẹ ọfẹ fún ọmọ rẹ, kíláàsì kínní dé ìkẹta alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀
À nì sẹ́, dan dan l’óúnjẹ ọfẹ fún ọmọ rẹ ,kíláàsì kínní dé ìkẹta alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀- Ìjọba àpapọ̀ Iléeṣẹ́ tó wà fún ìpèsè ohun ìrànwọ́ nílẹ̀ wa ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yìí nínú àtẹjáde kan tó fisíta lójú òpó abẹ́yefò Twitter rẹ̀. Àtẹjáde náà ní gbogbo Ìpínlẹ̀ tó wà ní Nàìjíríà ni wọ́n ti rọ̀ láti…
-
Ewì Toni: Ìwà rere
*Ìwà rere*Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà’bàjé ní jẹ́ k’ọ́mọ o j’ìyàẸwúrẹ́ ya aláìgborànÀgùntàn jẹ́ oníwàpẹ̀lẹ́Adígbánnákú ṣẹ̀yìn gákangàkan Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà rere lẹ̀sọ́ ènìyànÌwà rere ni òbí ní,tí wọ́n fi ń ǹpé ní òbí rereÒbí rere ló le kọ́mọ ní’wà rereÒbí rere ní fi ìwà rere kọ́ni Ìwà rere kọjá ẹ̀sìnẸ̀sìn bá ìwà rere láyé niKíì…
-
Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie
Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie Àwámárídìí ni iṣẹ́ Elédùwà, ṣùgbọ́n ọmọ èèyàn lọ́pọ̀ ìgbà má a ń fẹ́ tú fín ìn ìdí i kóòkò láti mọ kín gán án ní ń gbénú-un rédíò fọhùn. Bí kò bá wa rí bẹ́ẹ̀, kín ló mú kí Ìjọba àpapọ̀ ó máa dábàá àti…
-
Ènìyàn 148 míràn lárùn Covid-19 ní Nàìjíríà–Àjọ NCDC
Ènìyàn 148 míràn lárùn Covid-19 ní Nàìjíríà–Àjọ NCDC Ó ti pé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta àti márùndínládọ́jọ èèyan tó ti ní àrùn apinni léèmí yìí ní Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ Èkó ló ṣì ń léwájú.Ní bí a ṣe ń kó ìròyìn yìí jọ. Iye àwọn tí àyẹwò ti fihàn pé wọ́n lárùn apinni léèmí coronavirus lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tó…
-
Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ọlọ́pàá èwo n tèpè ni àṣà tó gbayé kan tẹ́lẹ̀ , ṣùgbọ́n ní àsìkò kòró yìí, ó dà bí ẹni pé wọ́n ti sún ilé iṣẹ́ ọ̀hún kan ògiri báyìí bí ó tí n ṣọ̀rọ̀ lókè ohùn látẹnu Kọmíṣọ́nnà ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ògùn pẹ̀lú kìlọ̀…