Category: Àṣà Oòduà
-
Kòrónáfairọ̀ọ̀sì kò dí ìgbáradì ètò ìdìbó ìpínlẹ Edo àti Òǹdó lọ́wọ́–INEC
Ó dà bí ẹni pé ń tí ń ṣe Lébáńdé kò s’ọmọ rẹ o, Lébáńdé ń sunkún ọmú, ìyá rẹ ń sunkún ebi, ló díá fún bí àjọ elétò ìdìbò Nàìjíríà ti kéde pé àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí coronavirus kò dí àwọn lọ́wọ́ rárá láti múra sílẹ̀ de àṣeyọrí ètò ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Òǹdó àti…
-
Aye̩ye̩ o̩jó̩ò̩bí Sikiru Lemon
Aye̩ye̩ o̩jó̩ò̩bí Sikiru LemonBí a bá dájó̩, o̩jó̩, á pé, bí a dósù, osù á kò. Gbogbo o̩jó̩ ko̩kàndínló̩gbò̩n, osù ké̩rin o̩dún ni o̩jó̩ò̩bí Alhaji Sikiru Lemon. Yorùbá bò̩,wó̩n ní “àìbá wo̩n sí níbè̩ ni àìbá wo̩n dá síi”. Ìwé ÌRÒYÌN ÒWÚRÒ darapò̩ mó̩ àwo̩n e̩bí, ò̩ré̩, ojúlùmò̩ àti olólùfé̩ láti sàjo̩yò̩ o̩jó̩ òní pè̩lú…
-
Èmi àti Olure̩mi yege àjàkálè̩ àrùn covid-19 – Tinubu
Asiwaju agba fun egbe oselu APC, Asiwaju Bola Ahmmed Tinubu ni oun ko ni arun ajakale coronavirus bi gbogbo eniyan se n gbee poori enu. O ni awon kan ni oun ti wa ni igbele olojo merinla pelu Oluremi. Awon kan tile ni oun ti ko aisan naa ni eyi ti o mu ki oun…
-
Ní Kàdúná, òfin kónílé ó gbélé yóò tẹ̀síwájú fóṣù kan
Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní bí iná ò bá tán láṣọ, ó seése kí ẹjẹ wọ̀rù wọ̀rù ṣẹ́kù lórí èékánná. À ti pé, ogun tí yóó bá wọ lé kóni, ọ̀nà la tií pàdé rẹ̀. Ìjọba ìpínlẹ̀ Kàdúná ti kéde àfikún iye ọjọ́ kónílégbélé f’oṣù kàn sí i . Gómìnà Nasir El-Rufai tó kéde ọ̀rọ̀…
-
Iwure AJE
Iwure AJE Toni. Aje wa fii ile mii se ibugbe ❗❗❗ Aje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki Aje pe le oa kin lOrisas Agede ni wo Ajenje lotu Ife ti o fi njo…
-
Ògúndá Méjì: Odù
Ògúndá Méjì.It is a fact that there is anxiety all over the World as a result of coronavirus pandemic. This is a challenge to all faiths. What else can we do other than supplication and offering. Looking at Odù, “Ògúndá Méjì, cast for today’s Òsè Ifá, Olódùmarè shall heal the World by sending out the…
-
Ọ̀ọni ilé ifẹ̀ bẹ̀rẹ̀ fínfín ìtagbangba ní Ifẹ̀
Ọọ̀nirìṣà ilé Ifẹ, jìngbìnì bí àtẹ àkún,Ọba Adéyẹyè Ẹnitan Ogunwusi bẹ̀rẹ̀ fínfín àwọn ìta gbangba gbogbo ní ìlú Ilé Ifẹ̀ lẹ́yìn tó kéde ríra àwọn ohun èlò afínko láti dẹ́kun ọwọ́jà àrùn apinni léèmí COVID-19. Ọba Adéyẹyè ra àwọn irinṣẹ́ afínko tí wọ́n ṣe lábẹ́lẹ́ tí owó rẹ̀ tó mílíọ̀nù mẹ́jọ náírà láti ṣe ìrànwọ́…
-
Olò̩tè̩ èmi àti Aláàfin máa fojú ba ilé-e̩jó̩ – Wasiu Ayinde
Gbajugbaja olorin fuji ti ina orin re si n jo lowo bayii ni o ti fa ibinu yo nigba ti won fesun kan an pe, o ni asepo pelu okan ninu awon olori Alaafin ti ilu Oya, Oba Lamide Adeyemi 111. Wasiu ayinde ni lati igba ti oun ti di Mayegun ile Yoruba ni awon…