Tag: Àṣà Yorùbá
-
Arábìnrin kan ni ó bí ìbeta léyìn odún métàdínlógún tí ó tí se ìgbéyàwó.
Arábìnrin kan ni ó gbe lo sí orí èro ayélujára tí a mo sí facebook láti lo pín ìròyìn ayò wípé òhun bí ìbeta láti bí odún métàdínlógún sèyìn. Ó ko síbè wípé… ” èyin abiyamo mi ò le mú ayo náà móra rárá, ègbón mi bí ìbeta ní àná léyìn odún métàdínlógún tí ó…
-
Àwon omo egbé APC ti Gúúsù Oyo ti jóòkó ìgbìmò – Abiola Ajimobi lo kí Alaafin Oyo.
Gómìnà ìpínlè Oyo , Abiola Ajimobi , tí ó ti fi okàn àwon omo egbé APC ti ìpínlè Oyo lókàn balè wípé omo egbé àwon ló ma wolé ní ibi ìdìbò tí ó n bò lónà ní odún 2019, àti wípé àwon ìlú ló ma dìbò fún won. Gómìnà náà ní ti lo kí Alaafin…
-
Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.
Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún. Olùsó Daniel Udoh, tí ó dá ilé ìjosìn “Agbejórò ni jésù” sílè ni owó sìkún ìjoba ti tè ní Akapabuyo, ìpínlè Cross river látàrí fífi tipátipá bá omo rè obìnrin odú méje lòpò. Udoh ni won ti fi sèsín…
-
Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.
Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC. Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Ogbeni Rauf Aregbesola ti gun orí ténté okò láti polongo egbé won, egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC fún ìdìbó ti odún 2018 ní ìpínlè Osun, ìpínlè omolúàbí.
-
Akékòó bìnrin méjì ja ìjàgbara látàrí òrékùnrin ní ilé-èkó gíga ifáfitì tí a mò sí Tai solarin University of Education, ní ìpínlè Ogun.
Fídíò àti àwòrán àwon òdóbìnrin méjì tí ó ñ jà látàrí òrékúnrin kan ni ó ti gbalè kan . Akékòó ni àwon arábìnrin méjì yí àti wípé akékòó ilé-èkó ifáfitì ti Tai Solarin University Of Education ni won, ìpínlè Ogun, won fi èsùn kàn wípé ìjà won dá lórí arákùnrin tí ó ñ se yáhoo…
-
Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.
Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé ti a mò sí Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè. Davido tí ó jé omo ogbó-n-tarìgì àti èèyàn ñlá, tí ó sì jé omo tí ó ti ìdílé olórò wà súgbón tí kò torí owó, orò bàbá rè má sisé mó, tí ó je wípé takuntakun ni…
-
Akékòó ilé-èkó gíga tí a mò sí Polytechnic ti ìlú Ede ní ìpínlè Osun ni àwon ará ìlú ti lù pa .
Ní àná ni akékòó ilé-èkó ti poly Ede fi okò pa ènìyàn bíi márùn-ún tí àwon omo tí ó sèsè fé wo ilé-èkó náà pélù okò rè. Bí ó tilè jé wípé, àwon ojú tí ó wà níbè náà so wípé ñse ni omokùnrin náà ti mu otí àmupara tí ó sì ti lo àwon…
-
Arábìnrin tí kò ju omo odún métàdínlógún (23) lo ta omo rè òsé méfà tí ó sí fi owó rè ra èro ìbánisòrò ní ìpínlè Edo.
Owó àwon agbófinrín ti te arábìnrin kan ní ìpínlè Edo tí ó jé ìyá omo méjì , Miracle Johnson, fún títa omo rè omo òsè méfà tí ó sì di owó náà ra èro ìbánisòrò fún ara rè. Gégé bí ìwé ìròyìn Punch se so, Miracle jé omo bíbí ilú Agenenbode ní Etsako ìjóba ìbílè…
-
Ajimobi àti Yinka Ayefele pàdé níbi ayeye Àádòrún odún (90) ojó-ìbí Olúbàdàn.
Ajimobi àti Yinka Ayefele pàdé níbi ayeye Àádòrún odún (90) ojó-ìbí Olúbàdàn. Ìyàlénu ñlá gbáà ni ayeye Àádòrún ojó-ìbí olúbàdàn ti ilè ìbàdàn tí a mò sí Oba Saliu Akanmu Adetunji ní ojó Àìkú. Gómìnà ìjoba ìpínlè Oyo Abiola Ajimobi lo síbi ayeye Àádòrún odún ojó-ìbí Olúbàdàn tí ìyàwó rè sìn ín lo, ìyàwó rè…
-
Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà .
Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà . Sineto Musiliu Obanikoro tí ó jé adarí àwon olúdábòòbò ti orílè èdè Nìjíríà télè ti lo kí baba wa Oònirìsà tí a mò si àrólé odùduwà ní ìlú ilé-ifè ní ojó mélòó séyìn. Èyí fi hàn wípé kò sí bí èèyàn se le tó Oba ba lórí…