Home / Àṣà Oòduà / Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.

Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.

Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.

Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Ogbeni Rauf Aregbesola ti gun orí ténté okò láti polongo egbé won, egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC fún ìdìbó ti odún 2018 ní ìpínlè Osun, ìpínlè omolúàbí.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo