Tag: Àṣà Yorùbá
-
Odún dé, ore yèyé òsun.
Òsun Osogbo tún ti dé lónìí tí se ojó ketaàdínlógún osù kejo odún, 2018, tí gbogbo àgbàyé fi n se odún fún Òsun éléyinjú àánú, igbómolè obìnrin Òsàyòmolè Nílé ìyà olúgbón won kò gbodò mawo Ìran arèsè kò gbodò morò Olúwa mi ló morò lósì mopa Òsun lo mopa tééré tí í pa won jé……
-
Gbajúgbajà òsèré Olu Jacob mò wípé àgbàtó omo ni mí báyìí ni Joke Silver se so.
Gbajúgbajà òsèré, Joke Silver so wípé nse ni olóògbé E.A Silver àti Dr.Abimbola Silver gba òun tó ni sùgbón nse ni kìí se wípé òun kò mò télè . Joke Silver so wípé nígbà tí ó yá ni oko òun mò wípé won gba òun tó ni. Bí ó tilè jé wípé won gba mama…
-
Ooni ti Ilè- ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi Enitan ti setán láti fé Tope Adesegun gégé bí olorì tuntun.
oni ti ilè-ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi tí òun àti olorì télè èyí tí a mò sí olorì Wuraola tí pínyà ní osú ògún tí a mò sí odù kejo odún 2017, nse ni ó dàbí baba ti rí olólùfé míràn. Nse ni ó dàbí eni wípé egbo ìfé baba ti san nígbà tí won…
-
Arákùnrin tí ó jé omo Ebonyi, ìpínlè kan ní orílè èdè Nìjíríà yí ti kú sí ilè Italy pélù àwon mókànlá míràn.
Èyí bani ní inú jé púpò, arákùnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà yí ti kú pèlú àwon mókànlà míràn ní inú ìjàmbá okò tí ó selè ní Foggia ní ilè Italy. Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé yí, orúko rè a máa jé Mr.Roman Mgbeke láti ìpínlè Ebonyi, tí ó lo sí ibi…
-
Omobìnrin kékeré yí ni won dáné sun nígbà tí won fi èsùn kàn án wípé àjé ni, ní ìpínlè Akwa Ibom.
Àwòrán tí ó wà ní ìsàlé yí ni àwòrán omobìnrin kan tí orúko rè a máa jé Queen, won dáné sun omo yí látàrí èsún tí won fi kàn án wípé Àjé ni. Anja Louvre tí ó jé panépané ní ìpínlè Akwa Ibom ní ó gba omobìnrin yí kalè, tí kò sì jé kí ó…
-
Àràbà Aworeni Adisa Makoranwale sun re.
òní tí ó jé ojó kokànlá osù kejo odún 2018 (11/8/2018) ni ètò ìgbé òkú baba wa tí ó sísè ní ojo ìségun tí ó jé ojó kokànlél’ógbòn osú keje odún tí a wà (31/7/2018) sí isà . Ìjo International Council for Ifa Religion (ICIR)pèlú àjo àwon láràbàláràbà ni ó se agbáterù ètò yí. Atèwònràn…
-
Timi Dakolo pín àwòrán ti ó rewà ti ìyàwó rè pèlú omo méta ní London.
Gbajúgbajà olórin ti orílè èdè Nìjíríà, Timi Dakolo ti pín àwòrán ìyàwó rè àti àwon omo rè méta ní ìlú London, ó ko síbè wípé “wón tun ti dé baba wón tún ti dé”. Timi Dakolo ti ó jé omo bíbí ìlú Accra ní orílè èdè Ghana tí baba rè sì jé omo Bayelsa ìlú…
-
Olorì Badirat Olaitan, ìyàwó Aláàfin Òyó kéreké parí ilé-èkó gíga ifáfatì ti ìlú ìbàdàn (university of Ibadan).
Olorì Badirat Olaitan, ìyàwó Aláàfin Òyó, Oba Lamidi Adeyemi kékeré, ti parí ifáfitì ní ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Ibadan tí a mò sí University of Ibadan. Bí omo bá dára ká so, ó ye kí á yé olorì sí lóòótó.
-
Ilé Ẹjọ́ Gíga Orílẹ̀-Èdè Braṣil: Ẹ Dáàbò bo Ẹ̀sìn Ìbílẹ̀ Aláwọ̀ Dúdú (Yoruba version by Akin Ogundiran)
Ilé Ẹjọ́ Gíga Orílẹ̀-Èdè Braṣil: Ẹ Dáàbò bo Ẹ̀sìn Ìbílẹ̀ Aláwọ̀ Dúdú (Yoruba version by Akin Ogundiran) Àbádòfin kan ti kalẹ̀ ní ìlú Rio Grande do Sul ní ilẹ̀ Braṣil tí yô ká àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ aláwọ̀dúdú lọ́wọ́kò láti máa pa ẹran rúbọ fún Òòṣà wọn. Ṣùgbọ́n àwọn ẹlẹ́sìn ìbílẹ̀ ti fárígá pé àbádòfin yí…
-
A kú àmójúbà *Oṣù Ògún (August) tuntun.* Oṣù ìdùnnú ni yóò jẹ́ láṣẹ Èdùmàrè
A kú àmójúbà *Oṣù Ògún (August) tuntun.* Oṣù ìdùnnú ni yóò jẹ́ láṣẹ Èdùmàrè. Gbogbo àdáwọ́lé wa ló máa yọrí sí rere. Aboyún ilé á bí wẹ́rẹ́, àgàn á tọwọ́ àlà bọ osùn. Gbogbo ẹni tó ń ṣòwò yó jèrè, wọ́n á bóde pàdé, bẹ́ẹ̀ wọn kò níí pàdánù. Oṣù Ajé suurusu ni yóò jẹ́…