Home / Àṣà Oòduà / Ooni ti Ilè- ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi Enitan ti setán láti fé Tope Adesegun gégé bí olorì tuntun.

Ooni ti Ilè- ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi Enitan ti setán láti fé Tope Adesegun gégé bí olorì tuntun.

oni ti ilè-ifè , Oba Adeyeye Ogunwusi tí òun àti olorì télè èyí tí a mò sí olorì Wuraola tí pínyà ní osú ògún tí a mò sí odù kejo odún 2017, nse ni ó dàbí baba ti rí olólùfé míràn.

Nse ni ó dàbí eni wípé egbo ìfé baba ti san nígbà tí won rí Tope Adesegun.

About Awo

One comment

  1. a dupe, OK congrat in advance

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?