Tag: Àṣà Yorùbá
-
Skolopad wo aso tí ó fi sósèjì se lo sí ibi láti gba àmì èye South African Feather.
Àwòrán tí ó gba èro ayélujára kan ti àmì èye south African Feather ti odún yi ni ìmúra àwon èèyàn kò bójúmu rárá. Olórin kan ní South African “Skolopad” wo aso tí ó kún fún sósèjì àti àpò èédú fún ayeye àmì èye yí.
-
Odunlade Adekola ti parí ìdánwò è ní UNILAG.
Gégé bí ó ti pin sí orí èro ayélujára (Instagram). ” Nígbà tí o bá parí ìdánwò, tí o wá n padá li sí ilé , tí o wá kó sínú súnkere fàkere oko, wà sà ya àwòrán, mo kí ara mi àti gbogbo akékòó ilé -èkó UNILAG wípé àseyorí nínú ìdánwò wa.
-
Ààre Buhari lo rí àwon omo egbé CAN ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.
Ààre Muhammadu Buhari ti lo rí àwon omo egbé Christian Association of Nigeria (CAN ) ní ilé ìgbìmò ní ìlú Abuja.
-
À n yan Àntà ( alligator ) tí a pa nínú oko ìresì wa.
Ìsinmi tòtè yí mà yàtà gan o, ó ti è ti dùn jù …járá oko yí mà da gan ni oo . Àwòrán obè aláta yéríyérí n bò láìpé.
-
Òdóbìnrin ni ó ya àwòrán orúko Runtown gangan sí ìdí rè.
Níbáyìí, ojú wo ni òrékùnrin rè ma fi wò ó tí ó bá rí ìdí òdóbìnrin yí?. Àwòrán tí ó ti gba èro ayélujára kan ni ti obìnrin tí ó ko orúko Runtown gangan sí ìdí rè. Olórin ìgbàlódé kan tí ó n jé Runtown tí orúko rè gangan n jé (Douglas Jack…
-
E wo ejò tí aládùúgbò mi pa, e jò wó kíni orúko rè.
Aládùúgbò mi ló pa ejò nlá yí ní kùtùkùtù òwúrò àná … Oúnje ti se.
-
Laura Ikeji Kanu tún yo ní àrà òtò.
Onísòwò aso àti olù gbé eré jáde, Laura Ikeji gbé lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí ó ya ni lénu yí.
-
Àwòrán ayeye ìsìnkú Obi Madubogwu.
Akoni òsèré , Obi Madubogwu tí ó kú ní ojó kejìdínló’gbòn osù kejo ( 28/8) nígbà tí ó jèrora ìtò súgà fún bí odún díè séyìn ni won ti sin sí ìlú rè ní Ogidi ìpínlè Anambra. Gbajúgbajà òsèré , Obi Madubogwu kú ní omo odún métàdínláàdóta (47). E wo àwòrán ìsìnkú rè.
-
Ajé omo Olókun.
Òrìsà ni olókun jé, a gbó wípé òun ni ó bí ajé, ó tún jé òrìsà orò àti ti ìsàlè òkun. Olókun ni ó n darí omi ó sì ní àse l’órí gbogbo ìsèdá inú omi . Olókun máa n fún ni ní orò , èmí gígùn abbl. Ajé olókun mo bè ó kí…
-
Nnamdi Mpiti tí ó jé akunjú (make up artist) pín àwòrán yí .
E má jé kí èrù bà wá . Kíkùn lásán ni , àti wípé èjè iró ni ó wà níbè “.