Tag: Àṣà Yorùbá
-
Àwòrán tí Tonto Dikeh àti Halima Abubakar yà tí won sì rewà nínú àwòrán náà.
Òsèrè orí ìtàgé, Tonto Dikeh gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí tí òun àti òré rè tímótímó , òsèré Halima Abubakar yà.
-
Àwòrán bàbá àti àwon omo rè obìnrin méfà.
Àwòrán bàbá kan láti orílè èdè Nàíjíríà pèlú àwon omo rè obìnrin méfà tí ó rewà. Baba tí orí rè wú pín àwòrán àwon omo rè obìnrin méfà. Won rewà gan ni. Nse ni ó dàbi kí èmi náà bí obìnrin.
-
Gómìnà ìpínlè Eko ti sí ojú ère ” ASA AROKOLO” ní ogonlonto ní Ikorodu lánàá.
Ère tí ó bù áyà tí ó fi àsà wa hàn ní Ikorodu ni Gómìnà ìpínlè Èkó ti báwa sí lánàá.
-
E wo ojú Davido ní orí ìtàgé nígbà tí obìnrin náà fi ìdí rù ú .
Kí ló n selè báyìí? Se Davido sèsè n bò ni ? Obìnrin ehn ! E wo bí Davido se n wò bí eni tí ó n lo sí àjùlé òrun re . Òrò kan fun un e jò .
-
Funke Akindele tún yo ní àrà òtò .
Funke Akindele tí gbogbo ayé mò sí Jennifer tún yo ní àrà òtò níbi àwòrán yí…
-
Peter Okoye se ayeye ojó ìbí fún Anita Okoye.
Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr P gbe sí orí èro ayélujára (Instagram) láti se ayeye ojó ìbí ìyàwó èkejì rè . Anita Okoye tí ó lé odún kan ní òní. Ó ko sí ibè wípé “O kú ayeye ojó ìbí re mama Ejima , igba odún, odún kan @ anita-okoye.
-
Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ògá olópàá yí àti ìyàwó rè Hausa yà.
E gbe yèwò àwòrán tí ó rewà kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ògá olópàá yí àti olorì tí a mò sí Hauwa yà . Won sì se jómírégí.
-
Alángbá nlá tí won pa fún obè aláta yéríyérí.
Gégé bí ò n lò èro ayélujára (Facebook) se pin. Ó so wípé òun pa Àntà( Alligator) nláyí ní àárò yí òun sì n wá àwon èlò tí òun yóò fi si láti se obè aláta yéríyérí. È yin èèyàn mi kí le rò ? Sé èyin le je èyí bí?..
-
Àwòrán ìsìnkú Akékòó bìnrin ti ilé-èkó gíga Auchi poly tí àwon figilanté yin ìbon pa. Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume .
Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume . Olóògbé Lawretta ni won pa… Kí olúwa te sí aféfé rere … Kí ó tó di wípé ó kú ó jé Akékòó Banking and Finance HND2(tí ó sèsè kékòó parí) . Olùkó àti Akékòó yóò ma se ìrántí re.
-
E wo ejò tí aládùúgbò mi pa ní ilé àyágbà rè.
E wo ejò tí aládùúgbò mi pa ní ilé àyágbà rè. O jé kó kúrò ní ilé àyágbé yí.