Tag: Àṣà Yorùbá
-
Gbiyanju lati toju obi i re !
Ojumo to mo wa lonii, ojumo ibukun, ojumo igbega, ojumo aseyori, ojumo ire, ojumo itunu, ojumo ayo, ojumo idunnu ni yoo je fun gbogbo wa lase Edumare(Ase). # AKARA IMORAN : Gbiyanju lati toju obi i re, niwon igba ti obi i re n be laye; eyin ti E ko ba ni obi laye mo, E…
-
Idajo mi ree…
Leyin gbogbo atotonu awon agbejoro mejeji ati iwadi to peye, ariipe ojebi esun ti a fikan e, nitori na idajo mi ree, ile ejo yi so e sinu: i) igbega; ii) aseyori; iii) idunnu; iv) ayo; v) ire owo; vi) ire omo; vii) alafia; viii) ati emi gigun, lati isinsin yi lo ati titi lailai……
-
Idile Alayo Toni
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. E wa nkan f’idi le abi ki e f’idi le nkan ki a jo gbadun…
-
Ogulutu Oro Toni
Hummmmmm mase beru #eniyan ju #Eledumare lo… woo orewa Kosi nkan tenikan o fi enikan Se,gbiyanjuy latile koju ota re loni,jeki o mo wipe Akinkanju eyan nio #nje O mo wipe toba ti nberu eyan ju yio pada sorare di Olodumare niwaju re.. #gbomi_Dada Kosiku tio pa agba taniba polo orire nbe….. Kunfun Adua kosi magbokan leniyan…
-
Eeto Owe L’esin Oro 4
Mo ki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro. Laakoko, mo dupe lowo Olodumare ti o funwa ni oore-ofe lati tun pade loni, leyin igba ti a dagbere fun eeto ni ose to koja. Moki kabiyesi olumoye ti ilumoye akoko, awon olori, moki awon oloye, gbogbo igbimo aafin ati awon omo’oba…
-
Olojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alagba Oluwakayode Olamilekan Adekoya Ijeni ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba. Okan pataki ni won je lara awon majekobaje ilu yi, oloye nla niwon laafin Olumoye. Balogun igbomekun oye ni mo nke si. OBA lori Ogun, mo ki yin e ku…
-
Ibeere Toni: laiye #Ijohun ati #Aye Ode oni
Ojuwo lefi wo asa ila kiko laiye #IJOHUN ati #AIYE_ISIN …..nje odara kamo ko omo wa nila bi???
-
Yoruba Du ‘n ka
Yoruba dun-un ka yoruba e komo yin o, ko tun le ko ko tun le so ede abinibi. A~ AJA, B~ BATA, D~ DOJE, E~ EJO, E~EYE, F~ FILA, G~ GELE………. A B D E E F G GB H I J K L M N 1 2 3 4 5 6 7 8 9…