Tag: Àṣà Yorùbá
-
Ogulutu Oro Toni – 16.06.2016
SI GBOGBO OBINRIN Hummm obinrin sowa nu oni oko(husband) o feran oun oti gbagbe pe iwa lewa omo eniyan abi Oti gbagbe wipe bi eso oko(farm) ba da ladaju eye oko lasan ni mo pada mu ru won je. Wonyi ni awon nkan ti o ma nda ile ru. 1.ejo inu ile ni riro 2.ope…
-
ko ko ko. Tani yen o?
Awa ni O! Eyin Wo? Awa Anu,Ire,Iyanu,Owo,OmO, Ayo,Ibukun,Alafia,Igbega,Aseyori,Aabo,Idunu,Itesiwaju, Ojurere Olorun at Emi gigun. Kini e wa o?. Awa lati wa ba iwo ati ebire/ore eyi ti o fe fun ire gbe lati odun yilo atii titi laiye… Ifa kan so ninu odu mimo iji elemere wipe.. Opa run ile baba mi bale oro wanran wanran…
-
Ire otun, ire osi, ire niwa..Iree o
Iree! Apa mejeeji l’eyele fi n ko’ree wo’le. Ire otun, ire osi, ire niwa, ire l’eyin, ire Olokun, ire Olosa, ko mi a da giriri wole to wa wa! Aase!
-
Idile Alayo Toni 09.06.2016
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. Beeni mo ki gbogbo awa musulumi ododo wipe a ku ongbe o, emi wa ti…
-
Odo Iwoyi – 3
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan f’idi le abi ki e f’idi le nkan ki a jo gbadun…
-
Sun re O! Henrietta Kosoko
Hummmmmm Erin wo ajanaku tisun bi Oke eyin ka ile Erin wo porogodo,okoko fo omi okoko danu haaaa sebi eyan Se nku re Oga oooo…….Orun mo kanju Ojo eda oni se ooo
-
#OkeItase2016! Preparation of the World Ikin
Ikin ifa agbaye/world ifa sacred palm but…we dem boys getting it ready for the festival… Yay??? See more photos after the page break
-
A ku ojumo oooooooo!
Oba to silekun ojo oni, yoo sina ayo fun wa, yoo sina aje fun wa, A ko no seru egbe wa, ire ayo wa ko ni fo wa ru(Ase). #AKARA_IMORAN : Ma se gbo oro okere, gbiyanju lati wadi ohun gbogbo daju, ki o si di eyii to je ododo ibe mu. Nitori oro okere,…