Tag: Àṣà Yorùbá
-
Igbeyawo Asofin Moji Lawal niluu Eko leku!
Arabirin Moji Lawal, okan ninu awon omo ile igbimo asofin ipinle Eko segbeyawo alarinrin lopin ose to koja yii pelu oko re, John Paul to je onisowo pataki. Arabirin Moji, eni to je obirin akoko ti o ma soju ekun Apapa nile igbimo asofin ipinle Eko naa lo je omidan kan soso laaarin awon asofinbirin…
-
E wo ohun ti Gomina Fayose n se laaarin oja
Gomina Ayodele Fayose da moto re duro loja Bisi to wa ni Ipinle Ekiti lati teti si edun okan iya arugbo yii nipa ohun ti won fe ki ijoba o se fun won. Gomina fara bale lati gbo gbogbo ohun ti iya naa fe so. O si seleri lati se atunse gbogbo ohun ti won…
-
Igbe aye Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi dun bi oyin
Laipe yii ni Oba Lamidi Adeyemi, Alaafin Oyo pe eni odun metadinlogorin. E le ka iroyin naa nibi: Lara awon foto ojo ibi baba mi-in to te wa lowo ni eyi ti baba ya pelu Olori Badirat Adeyemi, olori baba to kere ju lo. Bi Oosa Oyo tile ti dagbalagba, Olori Badirat, eni to sese…
-
Niluu Ilorin: “Awon osise mefa ti ku, awon kan wa nile iwosan”- Akowe egbe osise
Awon osise ajo olomi ti ipinle Kwara tu jade lojo Isegun to koja yii niluu Ilorin nigba ti won fi ehonu won han nipa owo osu won eleyii ti ijoba ipinle naa ko lati san lati inu osu keje seyin. Olayemi Olatilewa Yato si owo osu won, awon owo ajemonu kan naa tun wa lati…
-
“Eyin ni agbara ati isegun mi l’Ojoosegun”: Ipinle Oyo gba leta Ajimobi
Olayemi Olatilewa Gomina ipinle Oyo, Abiola Ajimobi ti gbe sadankata fun awon eniyan ipinle Oyo fun atileyin ti won se fun un lati segun niwaju ile ejo to n risi awuyewuye eto idibo to waye lojo isegun to koja yii. Asekagba ejo awuyewuye eto idibo gomina laaarin Ajimobi ati Rasheed Ladoja waye lose tokoja nibi…
-
Won Fadi Omo Odun Meji Ya Niluu Abuja
Olayemi Olatilewa Omokunrin eni odun merindinlogun (16) kan ti lo foju ba ile ejo niluu Abuja leyin asemase pelu omobirin, eni odun meji (2) kan. Iroyin yii lo jade nigba ti olupejo, ogbeni Adama Musa, eni ti n soju ile ise olopaa n se alaye naa niwaju ile ejo Gudu Upper Area Court to kale…
-
Owo te awon omo egbe okunkun niluu Ado-Ekiti
Olayemi Olatilewa Awon akekoo meji ile iwe gbogbonise ti ijoba apapo (Federal Polytechnic) to kale si Ado-Ekiti ati maanu kan ti n tu foonu se ni agbegbe naa ni won ti ko lo si iwaju ile ejo Majisireeti pelu esun wi pe won je omo egbe okunkun paraku. Awon akekoo oloju-ba-n-deru-bomo meji naa ni Efeotor…
-
Ireti Odegbami ja sofo lati di aare FIFA agbaye
OlayemiOlatilewa Bi o tile je wi pe ajo ere boolu ile Naijiria ti n fenu so wi pe gbagbaagba ni awon wa leyin agbaboolu to gba boolu metalelogun (23) sawon ni akoko ti n gba boolu fun orileede Naijiria, sibesibe ileri atileyin naa ko si ninu akosile kankan.Opin de ba erogba ati ala ogbontarigi…
-
“Bilionu lona bilionu owo naira ni Mimiko dabaru ni ipinle Ondo” – Alagba egbe APC
Olayemi Olatilewa Alaga egbe oselu APC eka ti ipinle Ondo, ogbeni Isaac Kekemeke ti fesun kan Gomina Olusegun Mimiko to je omo egbe oselu PDP nipa wi pe owo bi tirilionu kan naira (N1 trillion) ni gomina ti je mole lati nnkan bi odun mefa wa si akoko taa wayii. Oro yii ni Siamaanu yii…
-
Ooni tuntun wo ilu Ile-Ife tilu-tifon
Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti wo ilu Ile-Ife fun imurasile fun iwuye re ti o waye ni kopekope yii