Tag: iyawo
-

Iyawo Oloju Buluu
‘Kìí ṣe tìtorí owó ni mo ṣe fẹ́ gba Risikat padá, mo ní ìfẹ́ ẹ rẹ̀ ni ‘ Wasiu Jimoh, ọkọ Risikat tó ní ojú búlúù ní Ilọrin bá BBC Yorùbá sọ̀rọ̀, ìyàwó rẹ̀ náà fèsì. Ẹ wá gba ohun tí wọ́n wí.
-
Kini oma nda ija sileju laarin oko ati iyawo?
1, owo obe 2, ale yiyan 3, aigbora eniye (lack of understanding) 4, aini (poverty)
-
Haa Eyi tun ga ooo, to baje iwo ni kini wa se ?
Oko ka iyawo Ile e pelu Alee mo ori Ibusin won, to baje iwo ni oko yen kini wa se ?