Home / Aworan

Aworan

Artist: Moyo Okediji​

My motherWho walks in the nightGraceful be thy stepsAs you place your heelOn the head Of a hidden Cobra And it cannot bite you.

Read More »

Ogbè Até

Owó òtún mi ni mo fi n gba ire Adífáfún Sará Sará N’ílé olódùmarè la gbé n báwon Lóri orí eni òré òhun tìmùtìmù rere Àtélewó mi òsì Ni mo fi n gba ìfà Adífáfún Sèbí Sèbí N’ílé olódùmare ni ...

Read More »

Ará Ọ̀run

Cc – Moyo Okediji

Read More »

Foto: Aafin Ogbomoso

Aafin Ogbomoso

Read More »

Ifa physiology: Ojú/Eyes

Ojú. Ojú lalákàn fi í sọ́rí. Ojú oró ní í lékè omi. Ojú ò ní tì wá lótù Ifẹ yìí láíláí. Ojú ò níí relé de ìkankan nínú àwa ọmọ Awo. Eyes–Oju With the eyes, the crab watches the ori. ...

Read More »

IFA ANATOMY: Etí/ Ear

Etí. Ear, also fringe, edge, border, perimeter. Ó pawo lékèé Ó pÈṣù lólè Ó wá kọtí ọ̀gbọin sẹ́bọ Etí odò yato sétí aṣọ. Ọ̀rọ̀ tí a bá fẹ́ kí aditi gbọ́ Etí ọmọ rẹ̀ là á ti í sọ o. ...

Read More »

IFA ANATOMY: Itan / thigh

IFA ANATOMY Itan = thigh. A kì í bá ni tan ká fa ni ní itan ya. Because people are tied by kinship offers them no excuse to rip off the thighs of one another. `Moyo Okediji‎

Read More »

Oruko woni anpe nkan yi

Read More »

Eyin na ewo kini katipe eleyii

Read More »

Oruko wo ni alepe pasito ati afa yi?

Read More »