Category: Àṣà Oòduà
-
Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn
Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn Onírúurú aṣọ lára alágẹmọ, onírúurú ètè lápèjẹ sààráà lọ́jọ́ tí orí mádé, w nu agogo idẹ ní tií wà, ọrùn w’ọnú lèjígbà ìlẹ̀kẹ̀, àní lọ́jọ́ tó mú ìbàdì Àràbà Ògbó awo ,Oloye Ifalere Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 wọ Mọ́sàajì,aṣọ ọba tó taná yanran yanran . Ko sí agbe kọrọ…
-
Kí gbogbo àwọn olórí ààbò lọọ rọ́kún nílé – Ilé ìgbìmọ̀ asojú
Kí gbogbo àwọn olórí ààbò lọọ rọ́kún nílé – Ilé ìgbìmọ̀ asojúLáti ọwọ́ Yínká Àlàbí Abajade ipade ile igbimo asoju to wa ni Abuja ni “a kuku joye san ju enu mi ko ka ilu lo”. Won ni ki gbogbo awon olori eso aabo Naijiria lo sinmi nile. Won ni ko si ogbon atinuda kankan…
-
Jonathan sàbẹ̀wò sí Buhari
Ara iroyin yajoyajo to wole ni abewo ti Aare ana, Omowe Goodluck Jonathan se si Aare Mohammadu Buhari ni Aso Villa to wa ni oluulu Naijiria ni Abuja. Ipade bonkele ni ipade yii nitori pe awon mejeeji tilekun mori ni, won ko si ti so nnkankan fun awon oniroyin nipa ipade pajawiri naa. Láti ọwọ́…
-
Ìdíle Saraki àti ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara dájọ́ ìpàdé
Lẹ́yìn tí Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara ti tẹ̀lé òfin tí wọ́n wo ohun ìní ìdílé Saraki èyí tí wọ́n ń pé ibẹ̀ ni Ilé Arúgbó ní ìlú Ilorin, ìpínlẹ̀ Kwara, gbogbo àwọn tọ́rọ̀ kan nínú rẹ̀ ti wá gbà láti yanjú aáwọ̀ láì ti ọwọ́ Ilé ẹjọ́ bọ̀ ọ́ mọ́.
-
Àwọn Yèyélórìṣà, Akirè Shrine Ilé Ifẹ̀, 2003.
Pitcture was taken by Prof. Moyo Okediji in 2003, he returned to find the group in 2015. But for the two women at the extreme left, all the others had transitioned.
-
Asiwaju Sí Aso̩ Lójú Eégún “Operation Àmò̩té̩kùn” Láti O̩wò̩ Yínká Àlàbí
Asiwaju Bola Ahmmed Tinubu to je asiwaju agba ninu egbe oselu APC ni gbogbo aye ti n wa kiri lati ojo ti Abubakar Malami ti ni idasile Amotekun ko ba ofin mu.