Tag: Àṣà Yorùbá
-
Dangote fún àwon tí ó fi ara káásá níbi ìjàmbá iná ní ìlú Kano ní Mílíónú lóna èédégbéta náírà
Dangote fún àwon tí ó fi ara káásá níbi ìjàmbá iná tí ó selè ní ìlú Kano ní Mílíónú lóna èédégbéta náírà(#500,000,000)…
-
Aisha El-Rufai se àgbékalè ètò abéré àjesára àti láti lé ìta lo l’ára omodé.
Gégé bí Gómìnà ìpínlé Kaduna se pin, El Rufai. “Aisha El-Rufai ti se àgbékalè abéré àjesára àti ìpolongo láti lé ìta lo l’ára omodé.
-
Stephanie Coker tún yo ní àrà òtò, ó tún yanilénu nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà.
Stephanie Coker tún yo ní àrà òtò, ó tún yanilénu nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà. Stephanie Coker ti se ìgbéyàwó láìpé ojó, tí a bá ní p’aró ìgbéyàwó náà ye é…
-
Àwòrán tí ó yanilénu tí Hailey Adeleke yà.
Omobìnrin kejì ti gbajúgbajà olórin ní orílè èdè Nàijíríà , Davido , omo tí kò tíì fi esè kan ilè baba rè rí, ni ó ti n dàgbà sínú ewà , ó ti è ti rewà jù nínú àwòrán tí ìyá rè pín sí orí èro ayélujára.
-
Ìyà tí òyìnbó fi je ìran Yorùbá kò kéré.
Bí ó bá jé ti erú tí won kó wa ni kì bá da, bí kò se ikú burúkú tí won fi n pa àwon baba nlá wa. Béè won kò dá owó dúró. Kí Elédùmarè gbà wá lówó won.
-
Àwòrán okùnrin kan ní orílè èdè Cameroon tí ó pa àwon omo rè méta.
Yannick Arnauld Engolo láti orílè èdè Cameroon tí ó sì jé ènìyàn Swiss tí ó dá Miscas àti priceless corporation sílè ni a ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó pa àwon omo rè méta. Ó ti è pe akorin Chidinma sí ibi ayeye rè kan tí ó se, bí a se ri l’órí…
-
Àwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíye ti kéde wípé àwon kò se mó.
Àwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíyè ti so wípé àwon kò se mó nígbà tí won se ìwóde gbangba ní ìpínlè Èkó.
-
Mikel Obi fi àyè sílè bá àwon omo rè obìnrin méjì Ava àti Mia seré.
Olga, ìyàwó ògbóntàrigì agbá bóòlù Mikel Obi, pín àwòrán ara rè nígbà tí ó n bá àwon omo rè seré , tí ó sì n ka ìwé fún won .[starlist][/starlist][starlist][/starlist]
-
Bukola Saraki pàdé Akòwé Ìjoba gbogbogbò tuntun Boss Mustapha.
Ààre ilé-ìgbìmò asòfin Bukola Saraki pàdé Akòwé ìjoba gbogbogbò tuntun (SGF)Boss Mustapha.
-
Ambode wo okò ojú omi láti rin ìrìn àjò lórí omi .
Dr. Akinwumi Ambode, Gómìnà ìpínlè Èkó se ayeye láti we okò ojú omi tí ó sèsè rà, okò ojú omi náà sì wà fún ìpínlè Èkó, bí ó se so wípé àwon n sisé láti jé kí ìrìnàjò orí omi rorùn fún àwon àkànse isé…