Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán okùnrin kan ní orílè èdè Cameroon tí ó pa àwon omo rè méta.

Àwòrán okùnrin kan ní orílè èdè Cameroon tí ó pa àwon omo rè méta.

   Yannick Arnauld Engolo láti orílè èdè Cameroon tí ó sì jé ènìyàn Swiss tí ó dá Miscas àti priceless corporation sílè ni a ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó pa àwon omo rè méta. Ó ti è pe akorin Chidinma sí ibi ayeye rè kan tí ó se, bí a se ri l’órí èro ayélujára (Facebook) .

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?