Tag: Àṣà Yorùbá
-
Arákùnrin kan se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Èkó.
Arákùnrin kan ní orílè èdè Nàìjíríà tí a mò sí Jefferson Uwoghiren, se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Edo. Arákùnrin náà tí kò so ohun tí ó fé fi eranko afayàfà náà se, ni a rí tí ó ya àwòrán tí ó de òni náà ní enu bí ó…
-
Èsì ìdánwò wo ló dára jù tí o ti gbà gégé bi akékòó ifáfitì tí kò tì parí ?
Gégé bí akékòó tí kò ti parí ní ilé-ìwé gíga ifáfitì, àsìkò kan wà tí a ó rò wípé ayé ti ń se wá, àsìkò kan sì wà tí a ó rò wípé a ga ju ayé lo. Ohun tí ó le fa àsìkò yí ni tí èsì ìdánwò bá jáde. A ti gbó nípa…
-
Gómìnà Yahaya Bello ri èro amúnáwà (Transformer) gégé bí isé rè àkókò ní ìpínlè Kogi.
Gégé bí ìròyìn se so, Gómìnà ìpínlè Kogi: Yahaya Bello ri èro amúnáwà tí agbára rè tó Egbèédógún (300KVA) ní òpópónà kan ní Lokoja gégé bí isé rè àkókó léyìn tí ó ti lo odún kan àti ààbò lórí ipò. Ìkan lára ò n lò èro ayélujàra (facebook) tí ó pin àwòrán náà, ó Ko…
-
Owó te olùsó àgùntàn(pastor) èké kan nígbà tí ó ń gbìyànjú láti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé.
Olùsó àgùntàn èké kan tí a mò sí Osinachi Christopher láti ìpínlè Abia ni won fi s’èsín léyìn ìgbà tí owó ti tèé nígbà tí ó ń gbìyànjú à ti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé ní agbègbè Nnobi ní ìpínlè Anambra . Gégé bí eni tí ó pin se so èyí…
-
Ilé ejó gíga jù dá asòfin ìpínlè Taraba dúró, tí orúko rè ńjé Sani Danladi
Won pàse fun kí ó dá owó osù àti àláwánsì tí ó gbà. Ilé ejó gíga jù ti pàse fún asòfin tí ó ń sojú ilé asòfin àgbà àríwá ti ìpínlè Taraba sani Abubakar Danladi láti fi ipò náà sílè ní kíákíá kí ò sì dá gbogbo owó àláwánsì tí ó gbà fún Àádòrún ojó…
-
Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe.
Àwon Agbófinró ìpínlè Èkó so ònà tuntun míràn tí àwon gbómogbómo ńgbà jínigbe. Ní ìsàlè ni òrò tí agbenuso àwon Agbófinró ìpínlè Èkó, SP Dolapo Badmos so. “E jò ó tí enikéni bá fi káàdì ìpè ráńsé sí yín tí eni na sì pè padà wípé àsìse ni pé kí E fi ráńsé padà sí…
-
Àwon ológun yín ìbon lu omokùnrin odún márùn-ún ní Kaduna nígbà tí won ń ké ìrora won ní rowérosè ..
Gégé bí omo oòduà rere se so, omokùnrin odún márùn-ún tí orúko rè ńjé Hussein Mustapha ni àwon ológun yin ìbon lu nígbà tí won ń ké ìrora (rally) ní Kaduna láti fi àmì sí Qusday ní àgbáyé láti gba Zakzaky àti Palestine kalè (papàájùlo lówó ìkolù àwon Israel English Translation! Continue after the page…
-
Gómìnà Nyesom Wike dá òkan lára àwon Konmisôna rè dúró.
Gómìnà ìjoba ìpínlè River, Nyesom Wike ní òwúrò yí dá Konmisôna isé dúró ní ìpínlè rè tí orúko rè ńjé Bathuel Harrison (àwòrán eni tí ó wo jákèètì). Nínú òrò tí olùrànlówó pàtàkì rè so lórí ìtànná ohun Ìgbéròyìn jáde (Electronic media), Simeon Nwakaudu. Wike so wípé ìdádúró náà esèkesè ni; ó so fún Harrison…
-
Díè nínú ìsesí láti òdò Dino Melaye lórí ìròyìn èrò rè tí a se ìrántí láti ìgbìmò asòfin àgbà.
Ní àná, ìgbìmò tí ó ń darí ètò ìdìbò (INEC) gba àpò méfà tí ó kún fún ìbowólù àwon tí ó tó láti dìbò ní agbègbè Eokun ìwò oòrùn ní ilè Kogi, tí ó ń bèèrè fún ìrántí Dino Maleye láti ilé ìgbìmò asòfin àgbà. Nígbà tí ìròyìn náà wá, Dino gbe lo sí orí…
-
Ipò Burúkú Ti Ilé-ìwòsàn Ńlá Ní Warri Ní Ìjoba Ìpínlè Delta Wà.
Èyí ni ìròyìn ipò tí ilé-ìwòsàn ńlá wà ní warri ní ìjoba ìpínlè Delta wà lówólówó . Àwòrán na jé pínpín sí orí èro ayélujàra (facebook) English Version Continue after the page break