Home / Àṣà Oòduà / Gómìnà Yahaya Bello ri èro amúnáwà (Transformer) gégé bí isé rè àkókò ní ìpínlè Kogi. 

Gómìnà Yahaya Bello ri èro amúnáwà (Transformer) gégé bí isé rè àkókò ní ìpínlè Kogi. 

Gégé bí ìròyìn se so, Gómìnà ìpínlè Kogi: Yahaya Bello ri èro amúnáwà tí agbára rè tó Egbèédógún (300KVA) ní òpópónà kan ní Lokoja gégé bí isé rè àkókó léyìn tí ó ti lo odún kan àti ààbò lórí ipò.

Ìkan lára ò n lò èro ayélujàra (facebook) tí ó pin àwòrán náà, ó Ko síbè pé : ó lo pèlú okò tí ó tó ogún tí gbogbo rè férè jé SUV láti lo sí isé takuntakun tí ó se yí. Tí ó bá jé pé pípè padà wá Asòfin Dino Melaye yorí sí rere ni èyí ni kò bá jé isé àseyanjú rè kejì. Mo gbósùbà fún Gómìnà Bello !

Asòfin Dino melaye náà pín àwòrán yí tí ó so pé : àríyá ńlá bí Yahaya Bello se sí isé rè ààkókó láti ìgbà tí ó ti di gómìnà èro amúnáwà kan ní Koto pèlú Kápètì pupa. O so pé Allah ya isa kai!!!!!!!

Continue bellow for the English translation

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo