Tag: Àṣà Yorùbá
-
Annie Idibia da padà fún olùtèlé rè tí ó pè é ní omobìnrin tó “wor wor “.
Annie Idibia fi àwòrán yí sí orí èro ayélujàra rè (instagram) tí ó rò wípé kò rewà pè é ní omobìnrin tó ” wor wor ” . Ìyá omo méji tí òhun náà sì da padà fun pé :bí ìyá rè…. Continue after the page break for English Version
-
Falz àti 9ice je oúnje alé papò (àwòrán, fídíò).
Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè mó, nígba tí won ń fi òrò wa lénu wò . Falz àti 9ice pín…
-
Olúbàdàn kìlò kí won má se jàgídíjàgan bí odún egúngún se fé bèrè.
Gégé bí odún egúngún odoodún se ma bèrè l’óla, ojó ajé, ní ìlú Ibadan, ní ìpínlè Oyo, Olúbàdàn ti ilè Ibadan, oba Saliu Akanmu Adetunji ti pè fún àláfíà láti òdò àwon eléégún àti àwon tí ó ń tèle tí kò ní lò ju òsè méta lo. Oba Adetunji ti ń se odún egúngún l’ódoodún…
-
Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè
Àwòrán láti owó omo oòduà rere. Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè (a fé béè, èrín yakata). Ta ló tún n’ìfé àwòrán láti ìjìnlè ìlú yorùba? N’ísàlè ni àwòrán àjò lo sí ìlú Iseyin ní ìbèrè odún, mo se ìrántí kíka rè pé ilè wa kún fún wàrà àti…
-
Àwòrán : afurasí omo egbé òkùnkùn kan tí a mò sí Baddo ni owó tè ní Ikorodu.
Afurasí omo ògbó-n-tarìgì egbé òkùnkùn, Baddo, ni owó tè ní Ikorodu ní ìpínlè Èkó Lánàá tí osù kefà di ogbòn (June 30th) gégé bí àwon olùgbé àdúgbò se so, a rí Arákùnrin yí tí ó ń rìn káàkiri agbègbè Obafemi Awolowo, kí á tó dé ilé-ìwé Government Technical College Ikorodu, pèlú àdá àti àpò tí…
-
Ìjoba ìpínlè Èkó dá àwon òsìsé KAI dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won.
Ìjoba ìpínlè Èkó, lábé àse Gómìnà, láti jé kí ìlosíwájú bá ètò ìlera ti dá àwon òsìsé KAI (kick against indiscipline) dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won. Ìgbésè náà, gégé bí ìjoba ìpínlè náà, jé òkan lára ìsàkóso àwon ohun ègbin ní ìpínlè náà. Nígbà tí ó ń sòrò níbi tí won ti…
-
Olólùfé gbajúgbajà olórin Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re.
Àwon olólùfé gbajúgbajà olórin tí a mò sí Davido sòrò nípa irun abíyá rè tí kò fá. “Ra igi fífá-irun àádóta náírà (#50)nínú bílíònù lónà ogbòn re. Davido le jé eni tí àwon ènìyàn féràn sùgbón ìyan kò so pé ó kojá ìbáwí, tí ó bá ye kí á ba wí… Gbajúgbajà olórin, pín àwòrán…
-
Àyàngbàjù! Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Evans pe ògá olóòpá l’éjó,
**Àti Àwon Méta Míràn Látàrí Àtìmólé Rè Ní Gbogbo Ìgbà. Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Chukwudumeme Onuwuamadike tí ìnagije rè ńjé Evans, ó ti pe ògá olóòpá l’éjó, tí orúko rè ńjé Ibrahim Idris àti àwon méta míràn ní ilé ejó gíga ti ìpínlè Èkó látàrí àtìmólé rè ní gbogbo ìgbà. Àwon tí ó darapò mó ejó náà…
-
Oko mi fi mí sílè nítorí pé mi ò tí bímo. Okàn mi ń pòrúrú… Egbàmí!.
…Mi ò ti è mo bí mo se fé bèrè. Ó dàbí kí ń parí gbogbo rè. Oko mi sèsè fi mí sílè torí mi ò tíì bímo àti wípé kò fé kí won gba àtò rè àti eyin mi kí won so ó d’omo . A ti ń gbìyànjú fún odún kan àti díè.…
-
Àwòrán ilé-ìwòsàn Giginju àti irinsé orísirísi ti ilè Kano tí ó jé bílíònù lónà méji àti egbèrin néírà (₦2.8 billion)
Gómìnà ìjoba ìpínlè Kano ti ra irinsé ńlá fún ilé-ìwòsàn Giginju rè tí ó sèsè kó tán ní ìpínlè Ìjoba náà. Àwon irinsé náà ni 1.5Telsa Magnet Resonance Imaging, MRI machine, tí ó rà ní owó tí ó tó mílíònù lónà èédégbèrún, àkókó irú rè tí won ó kókó se sí ilé-ìwòsàn ìjoba ní orílè…