Tag: Àṣà Yorùbá
-
APINTANBI
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun Ku isimi opin ose eledumare koni jeki a fi eleyi se asemo o ase. Laaro yi mo fe so die nipa oro APINTANBI ti awon opuro ati alainimo babalawo miran nsope ki nse oruko toye ki won maa pe iyawo awa babalawo…
-
Isu Oro bale ro pee…
A da fun eji, ti o ma bowo fun iko Odidere, won ni ko kara nile, Ebo ni ko mu se. Ojo o ni ro ko pa ina iko Odidere, Iko Odidere d’Orisa. Ni Agbara Olodumare ati oruko Orunmila, Gbogbo ilara, ote, egan, ikorira, ati tembelekun awon ajogun ati elenini aye; Ko ni pa’na Ayo…
-
Otura Oriko, wa lo ree silekun ire temi fun mi! Aase!
Hoje também é dia de propiciarmos Olokun. Que a força e o Ase de Olokun abra as portas do progresso e da prosperidade a nossa família criando condições para que todos os obstáculos sejam retirados de nosso caminho. Ikan lowo Erede Odu lowo ikoko odi ni nsawo oke re fefe nijo ti ilekun ola ti…
-
Ewe Yi Je Òkan Lara Awon Ewe Ifa To Dara Pupo
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, emin wa yio se pupo re laye ase. Laaro yi mofe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi lati inu odu mimo eji elemere(irete meji), oruko ewe yi yio maa je okán, ewe yi je òkan…
-
Atitare/Itare: Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA
Aku ise ana o oni a sanwa o, aanu olorun Olodumare koni fiwa sile loni o ase. Laaro yi mofe ki e mo Pataki ewe towa ninu aworan yi ninu odu ifa OTURA ORILANA, ati iwulo e ti o se je ikan gbogi lara ewe ti a fi nwe ifa. Ewe yi je ewe…
-
Bi Ere BI Awada Oorun Odun 2016 n lo Ibi Ati Wo….
Ni iru akoko yi opo ile ise nla nla ni won ngbaradi ati se akosile asekagba ise iriju won fun odun ti nlo sopin yin… Beeni opo osise ile ise wonyi ti a ti fun ni gbedeke nibi ise won n sare soke sodo ki won ma ba padanu ise won… Bee gele ni awon…
-
Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan f’idi le abi ki e f’idi le nkan ki a…
-
A té o náá…
A té o náá. Hee, a té o náá. Kí o tún ara e té o. Awo kì nlé ikún. Awo kì nlé ejò o. A té o náá kí o tún ara e té. Awo kì nsúré gun igi òkókó o A té o náá kí o tún ara e té. Kí o má…