Tag: Àṣà Yorùbá
-
Orunmila ni awure emi naa moni awure
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si tun ku isimi opin ose adura wa yio gba o, ori buruku koni je tiwa o ase. Laaro yi mo nfe ki a mo iwulo ewe yi ninu odu ifa OSA ALAWURE, oruko ewe yi ni won npe ni ewe alukerese, ewe…
-
Oriki Ori
Ori Onise Apere Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja Ori ni seni ta a fi lo mosaaji aso oba Ori gbe mi Ori la…
-
Ikoja aaye pelu aimo iwon ara eni…
Mejeeji ko papo amoo won maa n wo tele ara wo leyin ni. Yorubo won ni, ikoja aaye nii mu ki fulani o kiri odo iyan. Aimo iwon ara eni naa nii sii muki abuke o ko ise atun’ko se. Emo je ki a koja aaye wa, ki a si mo se ju agbara wa lo..
-
Iwulo Ewe To Wa Ninu Aworan Yi Ninu Odu Ifa OGBEYONU,
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin Ku isimi oni emi wa yio se pupo re laye o ase. Loni mofe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi ninu odu ifa OGBEYONU, ewe yi wulo lopolopo to je wipe o maa ntu aye eniyan ro bi agogo…
-
Iwulo Ewe To Wa Ninu Aworan Yi Ninu Odu Ifa EJIOGBE
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, mogbaladura laaro yi wipe eledumare koni jeki enikookan wa jaye inira loni ase. Laaro yi mo nfe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi ninu odu ifa EJIOGBE, atiwipe bi mo se maa nso tele wipe ise babalawo ki nse ki a…
-
“Kíní ó ye’kú nùn l’Órí Awo?
Èjì Òyè Ifá ní ó ye’kú nùn l’Órí Awo What will avert death away from Awo? Èjì Òyè Ifa will avert death away from Awo.” ~Owó
-
Danrogbo ati Opapa
Danrogbo, Opapa, Owarowaro, Danrogbo ni won n pe iku, Opapa ni won n pe arun, Owarowaro ni won n pe ekun, Igbo loni ki ori wa gbo kaka di ale, Bi igbin ba dagba,a darugbo kegekege, Ki iku ma ji wa pa, Ki arun ma so wa lojo, Ki a ma ri oro ekun, Ki…
-
Eku Apere Ninu Ile Nla
Moki gbogbo apapo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi ooo Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (Ilosiwaju ishese lo jemi lo gun ooo) EJOWO OO E NPE MI SI AKIYESI Oruko mi ni iyin oluwa moje enikan tioma na owo die fun ololufemi latari wipe daddy mi lowo lowo emi nikan sini…
-
Aki Ijo Kinnihun Orunmila
(Atorieni Tikosun wonSe) TI ILU IBADAN LAPAPO OOO Aki gbogbo ojogbon awo mimo lapapo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi oo Wipe :- (KINNIHUN ORUNMILA O) (ilosiwaju ishese lo jemi lo gun o) Aki gbogbo apapo ojogbon awo mimo towa ninu ijo kinnihun orunmila ti ilu ibadan oo wipe eku ipade ijo kinnihun orunmila…