Tag: Àṣà Yorùbá
-
Orunmila Ni Olugbala Eda, Bee Naa Lo Si Tun Je Olugbala Fun Awon Irunmole Akegbe Re Naa
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Oni a san wa o, bi a se njade lo loni aanu eledumare koni fiwa sile o ase. Loni mofe ki e mo dajudaju wipe Orunmila ni olugbala eda, paapajulo awa adulawo bee naa lo si tun je olugbala fun awon irunmole akegbe re naa, idi eyi lo fi…
-
E gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila,
E jiire eyin eeyan mi, e je ki a gbo oro Olodumare ninu odu mimo ti Orunmila, mo nki lati inu Ogbe ‘gunda (Ogbeyonu ), o ki bayi pe,’ Bibi inu ko da nkan, suuru ni baba Iwa, agba to ni suuru, ohun gbogbo lo ni,a difa fun Orunmila lojo ti baba maa nire gbogbo,…
-
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi?
Eku ise ana o, a si ku popo sinsin odun o emin wa yio se pupo loke erupe ninu alaafia ara o, bi a se njade lo loni eledumare ninu aanu re yio fi iso ati aabo re bowa lowo ibikibi yio wu ko fe sele loni o ase. Eyin eniyan mi, mofe fi asiko…
-
Ekale ooo!!! Kin ni oruko ti a n’pe iwu ilu yi ni ile Yoruba?
Gbogbo eyin apapo olorire lagbaiye mini ile nla I.K.O. NLA wayi o lawujo apapo awon ojogbon awo mimo Fun idanileko Lori ASA ile wa Opolo eni kokan wa koni di oku o Ifa koni kuru lakaye eni kokan wa o Ejowo too Fun idanileko na fun gbogbo eyin olorire lagbaiye Kin ni oruko tiama npe…
-
Ejowo O Eyin Ojogbon!! Efun Wa Ni Imoran Lori Ala Yi O
Aki gbogbo eyin ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ILE NLA I.K.O. nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA.) Iye eni kokan wa koni ra ooo Ejowo ooo Ti obinrin basun tioba la ala wipe ohun pade were loju orun to nko enu ife si ohun ejowo too Kin ni itumo ala bee ooo
-
Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Toni Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan f’idi le abi ki e f’idi le nkan ki a…
-
Isebo ni isegun baa ti waye pa a ri, la a
ri ………Ohun gbogbo lowo ori eni. Ori mi ma pada leyin mi. Ojumo Ire o!
-
Ose tu’a
ko-mi-koro awo Ewi l’Addo Orun koko-ko awo Ijesa m’Okun Alakan nigbo ‘do t’eye ifá kerekere-kere adi’a fun Igba Irunmole ajikotun obu okan fun Igba Imole ajikosi alukin fun Orunmila nijo ti won ti Isalu orun bo wa Isalu aiye Eledumare niki won ma fi imo je Osun Orunmila nikan ni O fi imo je Osun…