Tag: Àṣà Yorùbá
-
Iwure Ojo Aje 3/10/2016
Ekaro oo se dara dara laji lowuro eni o gege bi emi na se ji oo toba ribee ejekia dupe lowo olodumare kiafi okan kan dupe lowo eleda wa ejekia bo si iwaju oke ipori wa pelu obi tabi eyi tinje orogbo kiadupe ore igba gbogbo kiawa bere fun alekun ore :- Oro yi se…
-
Olojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Princess Oluwakemi Morenikeji Idowu ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. Ni oruko Oluwa e o ni ba won…
-
Odu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe..
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Eku ojo meta o, Ogun lakaye yio bawa segun awon ota wa yio si lana ire gbogbo funwa loni ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Irete Osa kubu irete Osa kebe, irete Osa kenbekenbe a difa fun Ogun lakaye ejemu oluwanran omo adigirigiri rebi ija lojo to…
-
Ayeye Ojoibi Toni: Babami Oloye Olatbosun Oladapo
Ododun larorogbo Ododun lari awusa Ododun lati mo obi lori ate Ododun ni sapo nruwe Ododun ni peregun yio Ododun leo ma bee ninu ola ati Alaafia Alekun ogbon Alekun Oye Alekun IMO Alekun emi gigun Alekun Alaafia Oju asa ki i ribi Tawodi ki i roran Leyi toku teo lo laiye oju yin oni…
-
Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan f’idi le abi ki e f’idi le nkan ki a jo…
-
Ipade! Ipade! Ipade!
“Mo se ileri fun orisun mi Ti I se ile yoruba, Lati je omo yoruba atata nileloko, Ati lati je omo oko, Ti ki I f’owo osi Juwe ile baba re, Lati gbe ise, asa Ati ede yoruba laruge, Nibi gbogbo, ati kari aye, Ki oluwa ki o ran mi lowo, Lati mu ileri mi…
-
Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016
Hummmmmm ile eni lati nje ekute oni dodo, Morojo oko re feni kankan mo Tori Kosi bi tise o si oni kaluku naa nfaso bo tie ni wara o si loni, wara nbo lola Woo Orewa Kosokunrin tope nile aiye kaluku naa ngba kadara tie bee ni o Wa Gbomi Dada majeki enikan tio pa,majeki…
-
Yoruba Bo Won Ni Agbomojo Lomo N Moju…
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Ido Alayo ti ose yi. E wa nkan f’idi le abi ki e f’idi le nkan ki a jo gbadun…