Tag: Àṣà Yorùbá
-
Idile Alayo Toni – 17.09.2016 (E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo)
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku aseku odun emi wa yoo se pupo re laye, layo ati ni alafia ara. Mo si ki awa ololufe eto yi, wi pe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan…
-
Eyelé kìí léegun ìsé lára …
Eyelé kìí rìnrìn ìyà l’ésè Eye tó bá ye làá pè l’éyelé. Good morning Universe!!! May the blessing of today abide with each and everyone of us. Ase!!! Popoola Owomide Ifagbenusola
-
Olojo Ibi Toni – Arabinrin Adetona Banke
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Arabinrin Adetona Banke ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. Ni oruko Oluwa e o ni ba won na…
-
Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016
Hummmmmm erora gbogbo yan ale yan ale Nje O mo wipe ohunti ntan lodun eegungun bi? Woo Orewa Kosi nkan towa nta ju ohun towa nile lo bi Iwo naa ba toju titie dada yio rewa yio wuyi loju Gbomi Dada Tete se nkan tofe se loju Ojo maso arare di apere ajase tori gbogbo…
-
Awon ona wo ni a le gba lati gba ara wa si ‘le ni oko eru paapa ni owo awon oyinbo ati arabu?
English: What are the ways to free ourselves from the physical, mental and spiritual enslavement especially from the hands of Europeans and Arabs? Cc – Omo Oba
-
Odo Iwoyi: Oro Kan Ni Nrumi Loju Ti Mo Si Nilo Amoran Lori Re.
E ku ile ni a n k’ara ile, e ku abo ni a n k’ero ona, ti a ba ti rira eni tipe, e ku atijo ni a ma nki ara eni. Mo ki gbogbo ebi Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi, beeni mo ki eyin ololufe eto wa, eto yin, eto Odo…
-
Oju-Abe: Aare Mohammodu Buhari pase fun oga Agba Olopaa
Aare ile wa Nigeria, #Aare_Mohammodu_Buhari ti pase fun oga Agba yan-an-yan fun awon Olopaa nile wa lati tenu bo iwadii lori awon Ajo tiwon da sile lati maa pese Ounje ati Ohun-eelo fun awon Eeyan ti Iko-Onilakaadi-Ajajangbila #BOKOHARAM tiso di Alaini, Sugbon ti awon Ajo naa dari Ounje naa gba ibomiiran lo ki won si…
-
Omo Oodua Rere Nkan Semi Ose Idile Mi Pelu Nkan…
Omo oodua rere nkan semi ose idile mi pelu nkan lani ki majesi o ti oju obie re orun ara ma bo egbon mi jade laye ni ijeta ojo kinni osu kesan loju iyawa ha ha ha o ma se o igbe nla