Tag: Àṣà Yorùbá
-
Olojo Ibi Toni -04.09.2016
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alagba Daud Adewuyi ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. e o ni ba won na oja warawara nile…
-
Ogulutu Oro Toni – 04.09.2016
Hummmmmm eni taferi laferi kosojo taji tao reyan #nje O mo pe ohun ti ntan lodun eegungun? Woo Orewa Mo tori pe aiye nfe ooo loni kowa fitori re gbewu igberaga wo, nise loye komo se jeje tori oni suru ati oniwa irele nio jogun aiye yi Gbomi Dada Mase bawon waiye moya tori oro…
-
Ogulutu Oro Toni – 27.08.2016
Hummm bona kan o badi odamiloju pe ona Miran olela,iyen fun enito ba mo nkan ti nse. Woo Orewa Benikan ba sope sise re titan lodo ohun, mofe komope ose tie ni kose ti Olohun o, nise ni kode fila mowobe nitori riro nteniyan sise ntoluwa Gbomi Dada Eda lo nkanju ori okuku rebikan tori…
-
Ìfẹ́ láàárín ara wa
Ìfẹ́ láàrin ara wa Ìfẹ́ dára, Ìfẹ́ dùn bí a bá pàdé oní tí wá, Ìfẹ́ jẹ́ òhun tí ó má ń ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn, Yálà ọkùnrin sí obìnrin, Obìnrin sí ọkùnrin, Ìyá sí ọmọ, Bàbá sí ọmọ, Ọkọ sí ìyàwó, Ìlú sí ìlú, Orílẹ̀ èdè sí orílè èdè, Yálà o dúdú tàbí o…
-
Ìtẹ́lọ́rùn – #Ìtẹ́lọ́rùnṣepàtàkì.
Ìtẹ́lọ́rùn ni baba ìwà, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe pàtàkì fọ́mọ adamọ, Ìtẹ́lọ́rùn ṣe kókó, A gbọdọ̀ ni ìtẹ́lọ́rùn, Kí a le rí ayé gbé, Kí a le gbáyé ìrọ̀rùn, Aìní ni ìtẹ́lọ́rùn le mú ni jalè, Bí ohun tí a ni kò bá tó wa, Aìní ìtẹ́lọ́rùn ni mú nisẹ ṣìná, Ìyàwó rere wà nílè, Ṣùgbọ́n ojú…
-
Aṣọ wíwọ̀
Èèyàn lèyí ni àbí wèrè? Asínwín lèyí ni àbí abugije? Ṣé aṣọ lèyí abi kini? Ha! Ayé tí bàjé, Gbogbo ọmọ adáríhunrun tí sọ àṣà nù, A gbé òmíràn, A fi aṣọ sílè láìwọ̀, A sọ ìhòòhò rí rìn di ohun gidi, A rìn ìhòòhò nítorí oge, Kilode tí á lé wọṣọ iyì, Taa dáyé…
-
Ìfẹ́ – Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn
Ẹyín féràn ẹnu,ofi ṣe ilé, Irun féràn orí ,ofi ṣe ilé, Ìràwò òwúrò tèmi nìkan, Olólùfẹ́ mi, Nínú aba ayé yìí Ẹkuro emi mi alabaku ẹwa rẹ, Ọrọ ìfẹ́ yi n yimi Mo ni mi o nífẹ̀ẹ́ mon, Ife ìwọ olólùfẹ́ gbokan mi, Ìwo ni nkan rere ti o sele sì, Mo mọ ẹ ìmò…
-
#Òmìnira
Òmìnira ṣe pàtàkì, Òmìnira ṣe koko fún gbogbo ohun Òlódùmarè dá, Bí ènìyàn bá nínú ìnira tàbí ìgbèkùn, Tí ó wá rí ìtúsílẹ̀, Àyípadà rere a dé, Ìfọ̀kàbalẹ̀ á wà, A bọ lọ́wọ́ ìdarí ọ̀gá, A bọ nínú wàhálà ọ̀gá àti àwọn tí ó kó sódì, A le gbèrò fúnra rẹ, A ṣí le…
-
ARUGBA is no longer a Virgin maid
Arugba is not only seen as a virgin maid any longer, she is regarded a goddess herself and people make prayers and cast all their problem on her as she bears the calabash and passes on to lead the people to the river. 00ooreyeyeoo osunosogbo agbewaooooo..Ase!!! .She is a votary virgin(a cultural version of the…