Home / Àṣà Oòduà / Ìfẹ́ – Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn

Ìfẹ́ – Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn

Ẹyín féràn ẹnu,ofi ṣe ilé,
Irun féràn orí ,ofi ṣe ilé,
Ìràwò òwúrò tèmi nìkan,
Olólùfẹ́ mi,
Nínú aba ayé yìí
Ẹkuro emi mi alabaku ẹwa rẹ,
Ọrọ ìfẹ́ yi n yimi
Mo ni mi o nífẹ̀ẹ́ mon,
Ife ìwọ olólùfẹ́ gbokan mi,
Ìwo ni nkan rere ti o sele sì,
Mo mọ ẹ ìmò mi lékún,
Mo mọ ẹ ó jẹ kí mọ àǹfààní ohun tí ẹdua fún tí mo fi lè ṣe ọmọ aráyé lore…

Mo nife re…

Èyí wa fín àwọn olólùfẹ́ láti fi ranse sí olólùfẹ́ wọn

http://edeyorubatiorewa.blogspot.co.uk/2016/08/ife.html

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo